Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ÀGBÀ ÒFÒ SỌ Ọ̀RỌ̀ ÀDÁNÙ

Ó ṣeni láàánú pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni wọ́n pe’ra wọn ní àgbà ṣùgbọ́n ọpọlọ kọ́bọ̀ kò sí lórí wọn. Ní orí ẹ̀rọ Ayélujára ni a ti rí fọ́nrán kan níbi tí àwọn kan tí wọ́n pe ara wọn ní Yorùbá, tí wọ́n tún sọ pé àgbà ni àwọn, tí wọ́n nsọ̀rọ̀ aríremáse nàìjírà bíi pé Orílẹ̀-Èdè […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

NÀÌJÍRÍÀ TI KÚ..

Ìròyìn kan tí a rí lórí ayélujára instagram, tí ó wá tọ́ka sí ibi tí ọ̀rọ̀ náà ti jẹyọ lórí X, ìkànnì @winexviv , ni a ti ríi o, pé àwọn ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ girama ní ìlú aríremáṣe nàìjírà, èyí tí ìjọba agbésùnmọ̀mí wọn nfi àìnítìjú fi ipá dúró lórí ilẹ̀ wa ní Democratic Republic of […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌBÌNRIN BRIGADIER

Nínú ìròyìn kan tí a kà lórí ẹ̀rọ ayélujára nípa ọmọbìnrin olóògbé Brigadier Samuel Adémúlégún, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ṣọlápé Adémúlégún tó jáde fún if’ọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò nípa ìdìtẹ̀ gbà ‘jọba tó wá’yé ní ọjọ́ karùndínlógún osu Sẹ́rẹ́ ẹgbàá ọdún ó-dín-mẹ́rinlélọ́gbọ̀n, ní ìgbà tí arábìnrin Ṣọlápé yìí wà ní ọmọ ọdún mẹ́fà.  Ìpànìyàn tó ṣẹlẹ̀ lójú […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: YORÙBÁ SÍSỌ

Títí láé ni àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tó rán ẹni bí ọkàn Rẹ̀ sí wa, màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla láti gbà wa lọ́wọ́ amúnisìn àti láti dá wa padà sí orírun wa. Gẹ́gẹ́ bí màmá wa MOA ṣe máa ń ṣọ wípé, ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ MÁṢE BÁ Ọ̀TÁ D.R.Y NÍ ÀJỌṢEPỌ̀

Gbogbo ẹ̀yin tí ẹ lọ nforúkọ sílẹ̀, pé ẹ fẹ́ di ohunkóhun ní ìlú aríremáṣe Nàìjíríà, ìkìlọ̀ ré fún yín o! Gbogbo ẹ̀ pátá ló ní àkọsílẹ̀! Bóyá lẹ mọ̀! Ẹ máṣe rò pé Orílẹ̀-Èdè Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) kò ní mọ̀! Gbogbo ẹ̀ ni D.R.Y máa mọ̀, nítorí pé gbogbo ìwé-ẹ̀rí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌYÀ Ò DÁA LÁRA

Olódùmarè má fi ìyà ṣe tiwa nítorí, ìyà kìí ṣe omi ọbẹ̀. Fọ́nrán kan ni a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára tí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn tò láti gba iṣu ẹyọ kan ṣoṣo. Aò mọ ìlú tí ìṣẹ̀lẹ̀ yí ti ṣẹlẹ̀, ṣùgbọ́n àmọ́ pé ilẹ̀ Yorùbá ni, nítorí èdè Yorùbá ni wọ́n ń sọ. Ìkòríta tí ìjọba aríremáse […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌRẸSÌ LÁTÀRÍ EBI KẸ̀?

A ò mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ o, tàbí ibí gan-an tí ó ti ṣẹ’lẹ̀; ohun tí a ṣáà rí lórí ayélujára X, sọ pé “South West” èyí tí kìí ṣe orúkọ wa, ṣùgbọ́n tí àwọn tó ndá’ràn máa nsọ, dípò kí wọ́n pe Orúkọ wa, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), ni ó ti […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

AṢEMÁṢE CHINA!

Aṣemáṣe gbáà ni orìlẹ̀-èdè China àti àwọn ilé-iṣẹ́ aládani rẹ̀, bíi CCECC (China Civil Engineering Construction Company), àti àwọn míràn bẹ́ẹ̀ láti àwọn orílẹ̀-èdè ní Asia, nṣe báyi o, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y). Ìròyìn tí a rí fídíò rẹ̀ l’orí YouTube, fi hàn gbangba pé nṣe ni àwọn ilé-iṣẹ́ aládani […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

DÓKÍTÀ KỌJÁ ÀYÈ RẸ̀, L’ÁTÀRÍ ÌJẸGÀBA

Ṣebí ìjẹgàba ìjọba agbésùnmọ̀mí nàìjíríà, lórí ilẹ̀ Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), ló fa ìwà ọmọ-ìta tí  oníṣègun òyìnbó kan hù ní ilé-ìwòsàn ìjọba, ní Ijaye, ìlú Abẹ́òkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn orílẹ̀-èdè D.R.Y. Ṣe ni àgbà dókítà ọ̀hún, ẹni tó jẹ́ Abánidámọ̀ràn nínú iṣẹ́ eegun-títò,bu ìfọ́’tí lu akẹ́ẹ̀kọ́ nọ́ọ̀sì kan ní […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: IPÒ YÍYÀN

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y), gẹ́gẹ́ bí a ti mọ́ wípé lórí òtítọ́ àti òdodo ni a gbé ìpìlẹ̀ wa lé, nítorí náà, kò ní sí ojúsàájú nínú gbogbo ohun tí a bá ń ṣe, pàápàá ní àkókò yíyan adarí tàbí aṣojú, yálà ní ilé iṣẹ́ tàbí […]

Read more