Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ṢEYI MAKINDE ALÉTÍLÁPÁ

Ṣèyí Makinde aláìmọ èyí tó kàn ṣáà ń dá ọ̀ràn kún ọ̀ràn, bẹ́ẹ̀ ló ṣì ń tan àwọn ará ìlú pé òun sì ni gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ṣé ajá tí yóò sọnù kìí gbọ́ fèrè ọdẹ. Ìròyìn tó tún tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni pé, Seyi Makinde fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba kan ní ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀGÀBÀGEBÈ!!!

Ìròyìn kan g’óri afẹ́fẹ́ lát’orí ayélujára nípa àwọn òṣìṣẹ́ fún ìlú agbèsùnmọ̀mí nàìjíríà afipá jẹ gàba lórí ilẹ̀ wa, tó mú àwọn tó gbé òògùn olóró wọlé ní ibùdó ọkọ̀ ojù omi Tincan ní Apapa, wọ́n sì tún rí òògùn olóró nínú àwọn ọkọ̀ akérò tí àwọn míràn kó pamọ́ sí ilè ìkẹ́rù pamọ́ sí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

SÓJÀ LU ÒṢÌṢẸ́ KÁÌ NÍ ÀLÙPA

Nínú fọ́nrán kan ni a ti rí ọkùnrin tó nà gbalaja sínú àgbàrá ẹ̀jẹ̀ pẹ̀lú aṣọ iṣẹ́ àwọn elétò gbá’lúmọ́ ti ìlú Èkó tó wà lọ́run rẹ̀, àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ sì ń wòó láì mọ ohun tó yẹ kí wọ́n ṣe.  Ariwo! Wọ́n ti pá o ! Kò mí mọ́ o, ní ìkan nínú àwọn […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

WỌ́N TÚ ÀṢÍRÍ ARA WỌN

Ẹnikan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Ọ̀mọ̀wé Garus Gololo ni a gbọ́ pé ó sọ ọ̀rọ̀ kan, bóyá Haúsá ló ń sọ nínú fọ́nrán náà, a ò kúkú mọ̀! Ṣùgbọ́n, ìkànnì tí a ti rí ọ̀rọ̀ náà lórí ayélujára, sọ pé, Ẹ̀sùn márun ọ̀tọ̀tọ̀ ni Gololo yí kà sí ọrùn ààrẹ wọn Tinúbú ní […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ Ẹ̀KỌ́

Ètò Ẹ̀kọ́ ṣe pàtàkì ní Orílẹ̀-Èdè. Ṣebí kò sí ohunkóhun tí a lè fẹ́ẹ́ ṣe, tí kò ní síí pé, yálà a fi kọ́ ni, gẹ́gẹ́bí ẹ̀bùn àti’nú wá, tàbí a tún fi kọ́’ni náà, ní ojú ayé mbí. Ní ayé àtijọ́, ó ní bí àwọn babanlá baba wa ṣe máa nṣe oríṣiríṣi iṣẹ́ tí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ MÁ GBA OWÓ LỌ́WỌ́ NÀÌJÍRÍÀ

Ohun tí ó bá wu ènìyàn ni ó lè fi ìgbé-ayé rẹ̀ ṣe o! ṣùgbọ́n, ẹni a wí fún, ọba jẹ́ ó gbọ́! Ìròyìn tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára X, sọ pé ẹnikan tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Gbóyèga Isiaka, tí wọ́n sọ pé ó nṣojú “Àríwá Yewa àti Imeko-Afon“, Ìpínlẹ̀ Ògùn tí ó jẹ́ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ MÁA BỌ̀ NÍ’LÉ!

Ìròyín tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára X, ìkànnì @SaharaReporters, sọ pé àwọn agbésùnmọ̀mí ti gbé Agbaninímọ̀ràn dókítà fún àwọn obìnrin àti aláboyún ní ilé-ìwòsàn kan ní ìlú tó fẹ̀gbẹ́ tì wá, Nàìjíríà. Orúkọ dókítà náà ni Oníṣègùn Abídèmí Ọyárọ̀máde, tí ó nṣiṣẹ́ ní ‘Federal Medical Centre’ ní ìlú Gusau, ìpínlẹ̀ Zamfara ni ìlú àwọn […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

BÁYI NI Ẹ SỌ ỌMỌ YORÙBÁ DÀ!

Kò ní dáa fún àwọn ọ̀bàyéjẹ́, olóṣèlú àti gbogbo àwọn amúnisìn ìjọba nàìjíríà tí wọ́n nfi ipá jẹgàba lórí ilẹ̀ wa, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y). Ìjẹgàba yí ni ó ṣe okùnfà kí ìyà ṣì máa jẹ ọmọ Yorùbá títí di ìsiìyí! Láìpẹ́ yí ni a rí fọ́nrán kan tí ó fi hàn bí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

OWÓ-ẸYỌ ÀTI ÌTÚMỌ̀ ÒUN ÌWÚLÒ RẸ̀

Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ nkan ni àwọn òyìnbó amúnisìn ti yí mọ́ wa lọ́wọ́: gẹ́gẹ́bí Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá ṣe sọ, wọ́n ní àwọn amúnisìn wọ̀nyí kò jẹ́ kí á mọ ẹni tí a jẹ́ ní àgbáyé yí: bí a ṣe jẹ́ aṣáájú, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Wọ́n tún sọ, wọ́n ní àwọn nkan tó jẹ́ àṣà […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

OGUN ÀGBỌ́TẸ́LẸ̀

Ọ̀rọ̀ ogun àgbọ́tẹ́lẹ̀ ni o, wọ́n ní kìí pa arọ (tó bá gbọ́n). A ti sọ fún yín, sọ, sọ, sọ, a tún nsọ-ọ́ lẹ́ẹ̀kan si – gbogbo ìpínlẹ̀ Èkó, Ìbàdàn, Ògùn, Ọ̀ṣun, Ondó, Èkìti àti Ìṣèjọba-Ọ̀yọ́, kìí ṣe ara Nàìjíríà mọ́. A ti kúrò nínú Nàìjíríà láti ogúnjọ́ oṣù bélú ẹgbàá ọdún ó lé […]

Read more