Ọkọ̀ Òfurufú Aṣatọ́nà Abẹ́lẹ̀ Ibrahim Traore Ṣàwárí Ibùdó Ìkọ̀kọ̀ Àwọn Ológun Faransé Ní Orílẹ̀ Èdè Benin
Ìròhìn gbígbóná fẹlífẹ́lí kan lu jáde pé láti bíi oṣù díẹ̀ sẹ́hìn tí àwọn orílẹ̀-èdè Niger, Mali ati Burkina Faso ti lé àwọn ọmọ ogun Faransé jáde kúrò l’órílẹ̀-èdè wọ́n ni wọ́n ti ńwá ibi tí wón má fìdí ibùdó àwọn ọmọ ogun wọn kalẹ̀ sí ní Áfríkà. Kò sí ẹnití ó gbọ́ nípa ọ̀rọ̀ […]