ÈÈMỌ̀ WỌ̀’LÚ!! OBÌNRIN TÓ Ń TA ORÍ ÈNÌYÀN
“Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú fún mi, mi ò ní ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́, mi ò kìí se apànìyàn, ọrọ̀ ajé ní mo ṣe dé ‘bẹ̀.” Báyìí ni obìnrin kan ṣe ń sọ pẹ̀lú omijé lójú nínú fọ́nrán tí wọ́n ti nfi obìnrin náà han pé ó ń ta orí ènìyàn. Obìnrin náà ṣe àlàyé pé ọkùnrin […]