Ilẹ̀ Yorùbá, Agbára Ọ̀dọ́
Awọn bàbá wa sọ wípé, Ọmọdé gbọ́n, Àgbà gbọ́n, laafi dá’lẹ̀ Ifẹ̀. Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n sọ wípé, Ọwọ́ ọmọdé kò tó Pẹpẹ; ṣùgbọ́n, àgbàlagbà tí ọwọ́ rẹ̀ tó pẹpẹ nkọ́? ti ó bá gbé kèrègbè l’ati orí pẹpẹ, à ti mú nkan t’ó wà nínú kèrègbè náà nkọ́? Ọwọ́ àgbàlagbà ti tóbi jù l’ati […]