The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

OHUN AYỌ̀ DI Ọ̀RỌ̀ ÌBÀNÚJẸ́

Báwo ni ìbá ṣe dùn tó, ẹ̀yin Ọmọ Igbó-Ọrà, tí ó bá jẹ́ pé ní àkókò tí ó ti yẹ kí a lọ pàdé ìjọba-Adelé Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) ní ìlú Ìbàdàn, ní ọjọ́ kẹ́tàláá sí ìkẹ́rindín lógún oṣù igbe ẹgbàá-ọdún ó lé mẹ́rinlélógún yí, ni gbogbo wa […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

PÀTÀKÌ ÌWÒSÀN Ọ̀FẸ́ NÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ D.R.Y

Àwọn àdúrà tó ṣe kókó tí a máa ń gbà tí a bá fẹ́ kúrò ní ilé lọ sí ibikíbi láàárọ̀ ni pé kí Olúwa pa àlọ àti àbọ̀ wa mọ́,kí a má kan àgbákò. Fọ́nrán ọmọkùnrin kan ni a rí tò sì ba’ninínújẹ́ púpọ̀. Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ọ̀dọ́kùnrin yìí tọ́ka sí ìṣe pàtàkì […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

OÒGÙN ORÍ FÍFỌ́ KÒ LEÈ WO IBÀ

Èmi àti àwọn tó wà ní ipò ìsèjọba pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá ni a jọ máa ń lọ sí ibùdó àwọn agbésùnmọ̀mí láti lọ dúnnàá-dúrà, Gumi ló sọ gbólóhùn yí nínú ìròyìn kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́.  Ó wípé, kò sí ìgbà tí òun lọ sí ibùdó àwọn agbésùnmọ̀mí yí láì sí àwọn ìjọba àti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ARÍREMÁṢE NÀÍJÍRÍÀ YÁ ÀGBÁYÉ L’ÓWÓ

Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nsọ fún wa pé ọrọ̀ tí ó wà ní ibi tí wọ́n npè ní Nàìjíríà, kí àwa Yorùbá ti D.R.Y ó tó jáde níbẹ̀, tó kí ẹnikẹ́ni ó máṣe tòṣì. Ìwà-ìkà àti ìmúnisìn ni ó nṣe Nàìjíríà tí ayé fi le koko mọ́ ará-ìlú wọn, ṣùgbọ́n a dúpẹ́ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀGỌ́ ỌLỌ́PÀÁ NÍ FÁLỌMỌ, KÍ LÓ NṢẸLẸ̀?

Tani ó wó àgọ́ ọlọ́pàá tó wà ní Fálọmọ ní ìlú Èkó? Àwa ojúlówó Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) fẹ́ mọ̀ ẹni tí ó wo àti ìdí tí wọ́n fi gbé irú ìgbésẹ̀ bẹ́ẹ̀. Ìdí ni pé ìpínlẹ̀ Èkó ni Fálọmọ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÒTÍTỌ́ KÒ ṢEÉ BÒ MỌ́’LẸ̀

Bí irọ́ bá lọ lógún ọdún, ọjọ́ kan ni òtítọ́ yóò bá. Eléyìí ló bí ọ̀rọ̀ òtítọ́, tó ti ẹnu obìnrin aṣojú orílẹ̀ èdè Adúláwọ̀ kan jáde, tí a rí lórí ayélujára. Ọ̀rọ̀ obìnrin yìí ló dá bíi  ọ̀rọ̀ tí màmá wa, Ìyá Ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla sọ nípa ìwà àrékérekè àwọn òyìnbó láti ọdún mọ́ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

IKÚ ÒJIJÌ

Fọ́nrán kan tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ló ṣe àfihàn ọkọ̀ ojú omi kan, tó ń lọ láàárín agbami òkun, pẹ̀lú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn nínú rẹ̀, ó dájú pé àwọn èrò ọkọ̀ ojú-omi náà ti pọ̀jù, ṣùgbọ́n yàtọ̀ sí èyí, ìrìn-àjò wọn ọ̀hún kò rọgbọ rárá. Lójijì ni ọkọ̀ ojú-omi yí fẹ̀gbẹ́ lélẹ̀, lẹ́yìn èyí ni […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: IṢẸ́ ỌNÀ

Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, sọ ọ̀rọ̀ kan fún wa, nípa bí a ṣè wà kí òyìnbó-amúnisìn ó tó dé. Wọ́n ní wọ́n bá wa nínú oríṣiríṣi ohun tí ọwọ́ nṣe, gẹ́gẹ́bí àpẹrẹ, wọ́n rí ògiri tí ó jẹ́ ọgọ́run ibùsọ̀ máìlì (èyí tí ó jú ọgọ́run ibùsọ̀ kìlómítà lọ), tí ó sì jẹ́ ọ̀kan […]

Read more