Ọlọ́pa Nàìjíríà Dójúti Orílẹ̀-Èdè Wọn!
Wọn ò mọ̀ pé Òbìnrin òyìnbó láti ìlú Netherlands yí, nṣe fídíò wọn, ó sì nya fọ́tò wọn, àwọn kàn ri lórí alùpùpù tí ó ngùn lọ sí Ìlú Abuja ni, ní orílẹ̀-èdè wọn, Nàìjíríà; ni àwọn ọlọ́pa Nàìjíríà méjì ọ̀ún wá dáa dúró pé kí ó fún àwọn lówó! Ibi tí wọ́n ti nrẹ́rin, […]