ỌMỌ BÌNÍ SỌ BÍ NÀÌJÍRÍÀ ṢE WÁYÉ
Ọmọ Bìní kan lórí ẹ̀rọ ayélujára ló ṣe àlàyé bí ibi tí wọ́n npè ní Nàíjíríà kò ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè, àti pé kíkó tí wọ́n kó Nàìjíríà jọ, gẹ́gẹ́bí ilé-iṣẹ́ ìdókòòwò ni – Royal Niger Company, èyí tí ó di Unilever lóni. Èyí fi hàn wá, gedegbe, bí ó ti ṣe pàtàkì kí á wádi […]