• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ỌGBỌ́N JÌBÌTÌ TITUN TI JÁDE Ò!!

Ṣe a kìí gbọ́n tó ẹnití ń ṣọ́ ni, fún ìdí èyí a nílò láti máa kíyèsára nígbà gbogbo, ọkùnrin kan ló tú àṣírí ọ̀nà tuntun tí àwọn amóòkùn ṣèkà tún fi nlu jìbìtì báyìí nínú fọ́nrán kan lórí ayélujára láti sìn àwọn ènìyàn ní gbẹ́rẹ́ ìpàkọ́. Nínú àlàyé rẹ́, ó ní ṣàdédé ní àpò […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌWÁDI ÌJÌNLẸ̀ NÍ D.R.Y

Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ohun ni a nílò ìwádi-ìjìnlẹ̀ lórí rẹ̀, gẹ́gẹ́bí Màmá wa, Ìyà-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá ṣe sọ, pé a máa ṣe ìwádi àti àgbéjáde Ìtàn wá; bẹ́ẹ̀ ni a máa ṣe ìwádi àwọn ohun ìwòsàn abáláyé wa. Màmá wa sọ bákannáà pé gbogbo ẹni tí ó bá ní ẹ̀bùn fún òwò kan tàbí òmíràn tí ó […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

BILL GATES, APANI MÁ YỌDÀ

Ọ̀gbẹ́ni Klaus Schwab àti Bill Gates ní ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́jọ ló ń ṣe ìf’ọ̀rọ̀wérọ̀ lórí afẹ́fẹ́ amóhùn-máwòrán nípa àníyàn Bill Gates, ó ní òhún fẹ́ kí iye àwọn ènìyàn dínkù ní àgbáyé. Fún ìdí èyí, ó ti ṣètò onírúurú ọ̀nà láti pa ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn. Apànìyàn náà sọ lára ọ̀nà tó fẹ́ gbe gbà, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ TI GBA ÀLEJÒ Ọ̀ràn

Aò ní ríbi nílẹ̀ yí, ó d’òkèèrè! Ọmọ Yorùbá ẹ ṣọ́ra, ìránṣẹ́ ikú, Bill Gates tí wọlé sí ìlú aríremáṣe Nàìjíríà. Nínú ìròyìn tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti rí ìránṣẹ́ ikú ọ̀hún, níbi tí ó ti ń ṣe àlàyé fún àwọn ìránṣẹ́ tí yóò ló fún ìgbésẹ̀ yí. Ṣé aò gbàgbé pé láìpẹ́ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍA LÓ FA ÌWÀ ÀÌBÌKÍTÀ FÚN ARA ẸNI

Atótó-arére, ìkan nínú àwọn ọ̀dọ́ ní a rí nínú fọ́nrán kan tó ṣán kú lójijì ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀nà, àdúgbò Bádore Àjáh ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, D.R.Y tí ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà nfi ipá jẹ gàba lé lórí. Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn ló péjọ le ọ̀gbẹ́ni náà lórí tí wọn sì ń […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌFẸ́ ÀNÍJÙ ÀWA ÌRAN YORÙBÁ

Jẹ́jẹ́ ni wàhálà máa ń jókòó tí àwa ìran Yorùbá sì máa ń lọ fi gọ̀ǹgọ̀ fàá. Ṣebi àwọn àlejò tí àwọn babańlá wa gbà mọ́ra tí wọ́n sì tún fún wọn láàyè láti máa jayé fàmílétè-n-tutọ́ ló kó àwa ìran Yorùbá sínú wàhálà tí a bá ara wa lónìí yìí, tí kì bá ṣe […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ WÁ WO ÒGBÓJÚ OLÈ

Ọjọ́ tí wèrè bá ti mọ́ wípé wèrè ni òun, ọjọ́ náà gan-an ni ó ti ní ìwòsàn. Ọ̀rọ̀ yí ló dá lóríi fọ́nrán ọ̀kan lára àwọn gbéwiri ní ìlú akótilétà Nàìjíríà tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ndume, tó sì ń sọ báyìí wípé, òun kò ní kí wọ́n […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌṢÀKÓSO ÀLÙMỌ́NÌ ILẸ̀

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí òye kò yé, ni wọ́n ti béèrè pé “kí la máa jẹ,” “kí la máà mu,” àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ní Orílẹ̀-Èdè wa. Ọ̀rọ̀ yí kò rújú rárá; Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nsọọ́, láti ìgbà dé ìgbà, pé nísiìyí tí a ti polongo ìṣèjọba-ara-ẹni wa, tí a dẹ̀ ti ṣe […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÒYÌNBÓ TÚ ÀṢÍRÍ!

Òyìnbó kan ni o! Pẹ̀lú ìgboyà tó ní agbára gidi, ló fi tú gbogbo àwọn àṣírí òyìnbó ẹgbẹ́ rẹ̀. Ọkùnrin náà bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀, ó ní, ohun gbogbo ni ó lè yípadà ní ayé yí, ní àárín ogún ọdún pàápàá, ṣùgbọ́n ohun kan ni àwọn òyìnbó kò gbà kí ó yípadà o! Kíni ohun náà? Ìjẹgàba […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

FÚLÀNÍ ÀTI ÌWÀ ANINILÁRA WỌN

Ó mà ṣe o! Ìjọba agbésùnmọ̀mí ilẹ̀ Naijiria tó ń fipá jẹ gàba lórí ilẹ̀ wa ló fún Fúlàní ní ìgboyà láti máa kó àwọn màálù wọn wọ’nú oko – olókó tí àwọn ẹran náà sì jẹ oko éékà márùn-ún tí ó jẹ́ ti ilé-iṣẹ́ kan ní Ìpínlẹ̀ Ìbàdàn, ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti […]

Read more