ÈÈMỌ̀ WỌ̀LÚ, DÓKÍTÀ GBÀGBÉ ABẸ SÍNÚ ẸNITÍ WỌ́N ṢISẸ́ ABẸ FÚN
Obìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Okoye Ogochukwu tí o lọ fún iṣẹ́ àbẹ ní ilé ìwòsàn kan ni Àjàó Estate, ìpínlẹ̀ Èkó, l’Órílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y), tí apanimáyọdà Naijiria nfi agídí jẹ gàba lé lórí. Obìnrin yìí wípé nígbàtí dókítà Ejim ṣiṣẹ́ abẹ fún òun láti […]