A Ò NÍ KÚRÒ NÍNÚ OKO-ẸRÚ KAN, BỌ́ SÍ ÒMÍRÀN
Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìgbà ni Màmá wa, Ìyá-Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nsọ pé àwa ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), kò ní kúrò nínú oko ẹrú kan bọ́ sí ómíràn. Kíni ìtumọ̀ eléyi? Ní àìpẹ́ yí ni wọ́n tún mú ẹnu ba ọ̀rọ̀ náà, èyí tí […]