• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Àǹfààní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá: Orílẹ̀-Èdè Wà Kò Ní Jẹ Gbèsè

Màmá Ìran Yorúbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nfi yé wa pé ìkan nínú àwọn ọ̀nà tí àwọn amúnisìn fi máa nmú àwọn orílẹ̀-èdè ní ẹrú, ni nípa gbèsè jíjẹ. Àwọn ni wọ́n á fa orílẹ̀-èdè náà pé kó wá yáwo; àwọn ni wọ́n a sọ fun bí ó ṣe máa ná owó náà, àti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

OKÒÓ-LÉ-NÍ’GBA BÍLÌỌ̀NÙ DỌ́LÀ FÚN BURKINA FASO

Àwọn ará-ìlú Burkina Faso ti kó owó jọ o! Wọ́n ni àwọn ò gbára lé ìlé-ìfowó-pamọ́ àgbáyé, àwọn ò sì níí yáwó lọ́wọ́ Àjọ-Ayánilówó Agbáyé! Ibrahim Traore, olórí ìlú Burkina Faso fún’ra rẹ̀ ni a gbọ́ pé ó ti sọ eléyi tẹ́lẹ̀ nígbà tí ó dé orí aléfà ìlú náà. Bẹ́ẹ̀ ni ó wá gbé […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ WO BÍ ÌJỌBA ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ ṢE Ń FI ARA NI ARA ÌLÚ

A dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tó kó wa yọ lọ́wọ́ ìnilára àti ìfì’yàjẹni àwọn olóṣèlú ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, ṣé tí ìnira bá ti pọ̀jù kò sí ohun tí ènìyàn kò leè ṣe, èyí ló ṣe okùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ búburú kan tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí ọkùnrin kan tí fẹ́ gba èmi ara rẹ̀ lórí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

APA’NÁ ÒGO NI ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ

Ó màṣe o, àwọn ọ̀dọ́’bìnrin ní ìlú aríremáse Nàìjíríà tí di gbàǹjo tí wọ́n tún wà ń ṣe ìpolongo rẹ̀ lórí ayélujára. Nínú fọ́nrán kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti rí ìpolongo tí àwọn ilé iṣẹ́ kan ṣe nípa ohun tí ilé iṣẹ́ náà dá lé lórí, ǹjẹ́ kíni wọn ń ṣe […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Àǹfààní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá: Ojúse Ìjọba Fún Àwọn Ara Ìlú

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), gbogbo ojúṣe tó yẹ kí àwọn ìjọba ṣe ni wọ́n yóò máa ṣe, tí wọ́n kò sì ní yọ ọ̀kan sílẹ̀ nítorí pé, ìjọba wa yóò nífẹ̀ẹ́ àwọn ará ìlú bẹ́ẹ̀ni wọn kò ní jẹ́ kí ìyà jẹ ẹnikẹ́ni tàbí tẹ ẹ̀tọ́ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌTÀN IRỌ́ TÍ WỌ́N GBÉ FÚN WA

A ti gbọ́, a sì ti mọ̀, pé àwọn òyìnbó amúnisìn ṣe ohun aburú lọ́pọ̀lọ́pọ̀ sí àwa aláwọ̀dúdú, pàápàá sí àwa Ìran Yorùbá; wọ́n ké wa kéré lọ́pọ̀lọ́pọ̀, wọ́n sì wá ṣe bí ẹni pé àwọn ni ó là wá lójú, tí eléyi kò sì rí bẹ́ẹ̀ rárárárá. Gẹ́gẹ́bí àpẹrẹ, Ìṣèjọba Ọ̀yọ́ (Old Ọyo Empire), […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀKÓJỌPỌ̀ ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ LÓRI BILL GATES

@newscentral (a lo fọ́nrán yí fún ẹ̀kọ́ nìkan, a sì ṣe ìdánimọ̀ fún àwọn tí ó ní ẹ̀tọ́ lórí rẹ̀.) Ọ̀rọ̀ yìí dá lórí bí onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó, Dókítà Phillip Njemanze ti ṣe àtúpalẹ̀ ìgbésẹ Bill Gates lórí bí ó ti fẹ́ gba ọ̀nà ètò ìlera láti dín àwọn ènìyàn kù. Àwọn kókó tí dókítà […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ÀGBÀ-ÌYÀ TI FI ẸNU YÀGBẸ́!

Àwọn àgbà-ìyà tó pe’ra wọn ní “Yorùbá Council of Elders” ti tún fi ẹnu yàgbẹ́ o! L’akọ́kọ́ ná, ṣé ojú kì ń tì wọ́n ní? Ẹ jọ̀wọ́, ẹ bá wa béèrè lọ́wọ́ wọn pé, ṣé ọ̀run ni wọ́n ń gbé ni? nítorí ó dájú pé kì nṣe ayé yí ni wọ́n wà! Àgbà-ìyà yín, ẹ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

OLÈ TÚN TI MÚ OLÈ

Yorùbá ló sọ pé, Àìtètè m’olè, olè mú olóko. Ìbá ṣe pé a ti bọ́ sí’ta yanturu, ní ọjọ́ kẹ́tàlá, tàbí èyíkéyi ní ọjọ́ mẹ́ta tó tún tẹ̀le, ní oṣù igbe, ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rinlélógún tí a wà nínú rẹ̀ yí, ní ìlú Ìbàdàn, láti kí Ìjọba-Adelé wa káàbọ̀ ní oríkò-ilé-iṣẹ́ ìjọba D.R.Y, à […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Àǹfààní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Tí Yorùbá: Iná Mọ̀nà-Mọ́ná

Lọ́kan-ò-jọ̀kan ni àwọn àǹfààní tí yóò wà ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) nítorí pé màmá wa Ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla tí Olódùmarè lò láti gba ìran Yorùbá lóko ẹrú fẹ́ràn ìran wọn tọkàntọkàn tí wọ́n kò sì fẹ́ kí ìyà jẹ ọmọ Yorùbá kankan, àlàkalẹ̀ ètò ìsèjọba […]

Read more