NÀÌJÍRÍÀ, ṢỌ́RA!! DÁ ILẸ̀ YORÙBÁ PADÀ; JÁDE KÚRÒ LÓRÍ ILẸ̀ YORÙBÁ TÍ Ẹ GÉ MỌ́ NIGER àti KEBBI!
Ọ̀rọ̀ ti dójú ẹ̀, báyi o! Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, D.R.Y, gbé ohùn jádé: Nigeria, Ẹ JÁDE KÚRÒ LÓRÍ ILẸ̀ YORÙBÁ TÍ Ẹ GÉ MỌ́ ÌPÍNLẸ̀ NIGER YÍN àti ÌPÍNLẸ̀ KEBBI YIN! Ọ̀rọ̀ àṣẹ rèé o, láti Democratic Republic of the Yoruba. D.R.Y Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (D.R.Y) ti jáde kúrò nínú Nàìjíríà, […]