• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AṢỌ ÒKÈ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ

Yorùbá jẹ́ Ẹ̀yà àti Ìran tí Ọlọ́run dá pẹ̀lú ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ iyì àti ẹ̀yẹ nínú ìṣẹ̀dá wọn. Èyí ni ó fi jẹ́ wípé, ní ibi gbogbo àti ní ìgbàkúgbà, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ wípé ní gbogbo àgbáyé ni a ti dá ìran Yorùbá mọ̀ gẹ́gẹ́bí ìran t’ó wu’yì l’ọpọ̀l’ọpọ̀! Ọmọ Yorùbá ṣe oge dé’bi wípé àt’ọkùnrin àt’obìnrin […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ọmọ Yorùbá, Ẹ Ṣọ́’ra! àwọn ọmọ Igbo ti ntú ní ọ̀pọ̀ yanturu wọ ìlú Èkó

Ọmọ Yorùbá, etí yín mélo o? Ẹ ṣọ́’ra! Ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá kan l’ó sọ bẹ́ẹ̀ o. Ọ̀rọ̀ yí wá l’erèdí bí àwọn ọmọ Íbò ṣe ntú ní ọ̀pọ̀ yanturu lọ sí ìlú Èkó, l’erèdí wípé ilẹ̀ àwọn Íbò kò rọgbọ báyi o, nítorí ti àwọn agbé’bọn àìmọ̀ (unknown gunmen) àti bí wọ́n ṣe nsọ fún […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹrù ìjọ̀gbọ̀n ni ó nwọ’lé sí Ìlẹ̀ Yorùbá yío, Ẹ ṣọ́’ra

Arakùnrin kan l’orí ẹ̀rọ ayélujá’ra ní àípẹ́ yi, òun ni ó sọ o, wípé ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn àláìríkanṣèkan àtọ̀húnrèwá ni wọ́n nwọ’lé o, sí ilẹ̀ Yorùbá, lójoojúmọ́; èyí sì l’ewu l’ọpọ̀l’ọpọ̀ fún ìgbé-ayé-rere ọmọ Yorùbà àti ìlẹ̀ Yorùbá. Gẹ́gẹ́bí ohun tí arákùnrin náà sọ, ó ní òun gbọ́ wípé ọ̀pọ̀ nínú àwọn ẹrù ìjọ̀gbọ̀n yí wá […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Tí o bá fẹ́ sọ ẹ̀yàk’ẹyà di ẹrú, gba èdè àti ìtàn wọn – Wendall Donelson

Arákùnrin kan tí a mọ orúkọ rẹ̀ sí Wendall Kēñõ Donelson, l’orí ẹ̀rọ ayélujá’ra Facebook, l’o sọ o, wípé tí ẹnik’ẹ́ni bá fẹ́ sọ àwọn míràn di ẹrú, ó ní ohun mẹ́ta ni o ní l’ati gbà l’ọwọ́ wọn o, kí wọ́n tó lè di ẹrú l’abẹ́ rẹ. Èkínní, ó ní kí o gba Ìtàn […]

Read more