• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic republic of the Yoruba exit Nigeria on the 12th April 2024

Ọ̀rọ̀ Ti Di Orílẹ̀-Èdè S’orílẹ̀-Èdè

Kí ẹnikẹ́ni ó má ṣe tan ara wọn jẹ mọ́ o! Ọ̀rọ̀ ti di ti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè, l’ati ọjọ́ kéjìlá oṣù kẹ́rin, ọdún 2024 tí a wà nínú rẹ̀ yí. Ọ̀ràn nlánlà ni nàìjíríà ndá níwájú àgbáyé o! Ohun tí a npè ní ìṣèjọba-ara-ẹni (Sovereignty) ní agbára púpọ̀ ní gbogbo àgbáyé, àti wípé, l’ati […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Kíni A Npè Ní Ay’edèrú Onjẹ?

Ẹ jẹ́ kí a ṣọ́’ra fún irúfẹ́ onjẹ tí a njẹ, ní àkókò yí. Nígbàtí a bá ti lé àwọn agbésùnmọ̀mí ìj’ọba Nàìjíríà kúrò l’orí ilẹ̀ wa tán, ìj’ọba Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá máa ri dá’jú wípé gbogbo ohun tí a máa máa jẹ s’ẹnu ní ilẹ̀ Yorùbá máa jẹ́ inkan tí kò l’ewu […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ilẹ̀ Yorùbá Kìí Ṣe Fún Àjèjì Kankan!

Àwọn ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá ti f’ọhùn já’de o! Wọ́n ní gbogbo Ilẹ̀ Yorùbá, l’ati Èkó dé Ìbàdàn, títí dé Ògùn, dé Ọ̀ṣun, dé Ondó, dé Èkìtì, dé Ìpínlẹ̀ Ìṣèjọba Ọ̀yọ́ (Old Ọyọ Empire; èyí tí àwọn kan mpè ní Kwara àtí Kogi, tẹ́’lẹ̀, ní apá ìwọ̀-oòrùn Odò Ọya); ti ọmọ Yorùbá ni o! Wọ́n ní […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ọmọ Yorùbá Ṣe Ìkìlọ̀, L’ẹẹ̀kan Si, Fún Òṣínbàjò

Àkókò ìkìlọ̀ l’a wà yí o! Ẹni a bá wí, Ọba jẹ́ k’ó gbọ́! Ṣé kòì tíì pẹ́ s’ẹhìn, tí àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá ṣe kìlọ̀kìlọ̀ fún agb’ẹjọ́rò, Òṣíbàjò, wípé kí ó ṣọ́’ra l’ati má ṣe da’ra pọ̀ pẹ̀lú àwọn Fúlàní Nàìjíríà tí wọ́n fẹ́ lòó l’ati ṣe àtakò ìran Yorùbá, l’atàrí wípé wọ́n fẹ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ajílẹ̀ Aburú Ti Ba Nkan Jẹ́ Ní Ìlú T’ó F’ẹ̀gbẹ́ Tì Wá

Ìròyìn kan t’ó tẹ̀ wá l’ọwọ́ sọ wípé, ilẹ̀ Yorùbá ni wọ́n ti ngbìn ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ erè oko tí a rò wípé nàìjíríà l’ọhún ni wọ́n ti nko wọn wá sí ilẹ̀ wa! À b’ẹò ri! Ní nkan bí àádọ́ta ọdún s’ẹhìn, ìlú nàìjíríà nígbànáà kó ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ ají’lè wọ’lé l’ati òkèèrè, tí wọn kò sì ṣe […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ayédatiwa, Kúrò L’orí Àlééfà Ọmọ Yorùbá

Ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá l’ó sọ bẹ́ẹ̀. Ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá kan l’ó sọ wípé, Àpapọ̀ ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, sọ fún ẹ, ìwọ Lucky Orímisàn Ayédatiwa, tí o pe ara rẹ ní gómìnà ìpínlẹ̀ Ondó; oò kìí ṣe gómìnà ìpínlẹ̀ Ondó o! Ìwọ l’o pe’ra ẹ bẹ́ẹ̀! Lucky Orímisàn Ayédatiwa, kúrò l’orí àlééfà ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ìjọba Agbésùnmọ̀mí Ṣe Òfin Oní’lé-Gbé’lé Ní Èkìti!

Ìpínlẹ̀ Èkìtì jẹ́ ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, l’abẹ́ ìṣ’àkóso Ìjọba Adelé Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, pẹ̀lú Mobọ́lájí Ọláwálé Akinọlá Ọmọ́kọrẹ́ tí ó jẹ́ olórí ìjọba adelé orílẹ̀-èdè Yorùbá. Ṣùgbọ́n àwọn ìjọba agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà (ìjọba tẹ́rọ́síìs) tí wọ́n fi ipá dúró l’orí ilẹ̀ wa, ilẹ̀ Yorùbá, tí agbésùnmọ̀mí apàà’yàn Oyèbánjí tí nàìjíríà npè […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àgbà’yà, Bísí Àkàndé Gba Ipò Pro-Chancelor (Al’aga Ìgbìmọ̀) Fásítì Ìbàdàn

Tí a bá ns’ọ̀rọ̀ àwọn t’ó jẹ́ Àgbà’yà ní ilẹ̀ Yorùbá, l’oní, Bísí Àkàndé, tí ó ti f’ìgbà kan jẹ́ gómìnà ìpílẹ̀ Ọ̀ṣun rí, jẹ́ ìkan gbòógì, nínú wọn! Ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá ló sọ eléyi, l’atàrí ọ̀rọ̀ kan tí akọ̀ròyín kan fi sí orí ẹ̀rọ ayélujá’ra. Bísí Àkàndé jẹ́ ọmọ ọdún márun-dín-l’aádọ́run; ó ti pé […]

Read more