• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ó Gbẹnu Tán: Ẹ Wá Wo Bí Wọ́n Ṣe Ń Kó Gbogbo Agbára Sí Ọdọ Ara Wọn Ní Orílè-Èdè Nàìjíríà

Báwo ni ẹ ṣe fẹ́ kí ìdájọ́ òdodo wà ní orílè-èdè Nàìjíríà, ìjọba mọ́ mí kí ń mọ̀ ọ́ ni wọ́n ń fi ìjọba Nàìjíríà ṣe, a rí àṣírí èyí nínú ìj’ọ́mọ ènìyàn Justice Kayode Olú Ariwoọlá, kété ti wọn ti búra fún un tán gẹ́gẹ́ bíi adájọ́ àgbà ní orílè-èdè Naijiria ní ọjọ́ kẹta […]

Read more
Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá

ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ NÍ ÌLÚ NIGERIA TI R’ỌRÀN O!

A kì í s’òótọ́ inú, kí ọ̀rọ̀ ẹni má d’ayọ̀, b’áyé ẹni bá dojúrú ìwà èèyàn ló yẹ ká wò Òwe Yorùbá Ètò ẹ̀kọ́ ní ìlú tí ó fẹ̀gbẹ́ tì wá, èyíinì, Nàìjíríà, ti wá kúkú polúkúrúmuṣu báyi o! Gẹ́gẹ́bí ìròhìn kan tí a gbọ́ ti sọ, ọmọ apá òkè Ọya kan ní ìlú Nàìjíríà, […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Èèmọ̀ Wọ’lú O! Tàbí Ká Sọ Wípé Ó Ti Fẹ́ẹ́ Wọ’lú Ni, Tàbí Ó Ti Nwọ’lú Bọ̀?

Èèmọ̀ Wọ’lú O! Tàbí Ká Sọ Wípé Ó Ti Fẹ́ẹ́ Wọ’lú Ni, Tàbí Ó Ti Nwọ’lú Bọ̀? Ṣé l’aìpẹ́ yí ni a gbọ́ l’orí ẹ̀rọ ayélujá’ra bí ètò ìdìbò ṣe lọ ni ìlú South Africa, tí ó ti’lẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n ni òyìnbo aláwọ̀ funfun pàápàá r’ọwọ́ mú l’ara ètò ìdìbò náà. Ṣé ohun tí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

A NÍ L’ATI ṢỌ́’RA GIDI FÚN OYÍNBÓ

Ó ti wá d’ojú ẹ̀, pátápátá báyi o, Ọmọ Yorùbá, ṣé ẹ mọ̀ wípé a ti ní ìjọba tiwa ní ìsinìyí, a sì ní l’ati bo’jú tó ara wa, gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè. Àwa ni a fẹ́ òmìnira o, a sì ti ri. Ní òtítọ́ àti ní òdodo, àgbékalẹ̀ (èyíinì, àlàkalẹ̀, tabí BluePrint) fún Orílẹ̀-Èdè Olómìnira […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AGBÁRA AMẸ́RÍKÀ DÍN KÙ NÍ ÌWỌ̀-OÒRÙN AFRÍKÀ

Ìròhìn nípa bí agbára ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ọlọ́pọlọ pípé orílẹ̀ èdè Amẹrika ṣe n dínkù síi ní agbègbè ìwọ̀ oòrùn Afrika latàrí bí wọ́n ṣe kúrò ní orílẹ̀ èdè Niger. Ìwé ìròyìn ayélujára kan tí a npè ní Reuter gbé ìròyìn kan jáde ní ọjọ́ karundínlọgbọ̀n oṣù òkúdù, ẹgbàá ọdún ó lé mẹrinlélogún ti sanmoni òde òní latari […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ̀rù Mba Àwọn Olórí Orílẹ̀-Èdè Ní Áfríkà

Ìròhìn kan tí ó tẹ̀ wá l’ọwọ́ l’orí ẹ̀rọ ayélujá’ra, l’ó sọ wípé, ẹ̀rù ti mba ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ àwọn olórí-orílẹ̀-èdè ní Áfríkà o! àti, ní pàtàkì jùlọ, ìwọ̀-oòrùn Áfríkà! Njẹ́ kíni èrèdí eléyi o? A gbọ́ wípé nṣe ni ìbẹ̀rù-b’ojo ti wá bá wọn, báyi o, l’atàrí bí wọn ò ṣe mọ kíni ààrẹ ìlú Burkina […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àwọn Olóríburúkú Ọba Nko’ra’wọn Jọ L’ẹhìn Tí Wọ́n Ti Ta Yorùbá S’oko Ẹrú Tán!

À b’ẹ ò rí nkan! Àwọn olórí burúkú gbogbo tí wọ́n pe’ra wọn ní Ọba ní ilẹ̀ Yorùbá, np’ètep’èrò wípé àwọn fẹ́ kó ara wọn jọ l’ati jà fún ìran Yorùbá, àti l’ati wá nkan tí kò sọnù, l’ẹhìn ìgbà tí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ti dúró tán (D.R.Y) gẹ́gẹ́bí Orílẹ̀-Èdè aṣè’jọba-ara-ẹni (Sovereign Nation) […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá: Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá Gba Ìkìlọ̀!

Àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá káàkiri ìpínlẹ̀ méjèèje Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ti gba ìkìlọ̀ l’orí àwọn irúgbìn ayédèrú tí ìjọba agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà tí ó ngàba lọ́wọ́lọ́wọ́ báyi lorí ilẹ̀ wa, npín fún wọn! Ìròyìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ sọ wípé àwọn ìrúgbìn ayédèrú wọ̀nyí ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ síí tà, lówó pọ́ọ́kú fún […]

Read more
Democratic republic of the Yoruba exit Nigeria on the 12th April 2024 Yoruba nation is no longer nigeria

Kíka Ilẹ̀ Yorùbá Mọ́ Nigeria Jẹ́ Ọ̀ràn-Dídá – D.R.Y

Ó ti wá d’ojú ẹ̀ báyi, o! Àwọn ọmọ ènìyàn ndá ọ̀ràn mọ́ ọ̀ràn, ní ilẹ̀ Yorùbá; bóyá àìm’ọ̀kan l’o nṣe wọ́n ni o, tàbí àf’ojúdi ni o, tàbí ìjọba ìlú t’ó f’ẹ̀gbẹ́ tì wá, èyíinì, nàìjíríà, l’ó rán wọn ní’ṣẹ́ ni o, èyík’eyí t’ó wù k’ó jẹ́, kò kàn wá; ṣùgbọ́n a fẹ́ kí […]

Read more