The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌFỌ̀KÀNBALẸ̀ WÀ FÚN GBOGBO I.Y.P

Lára ànfààní Orílẹ̀-Èdè Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) fún gbogbo àwa ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti D.R.Y, tí a sì fẹ́rẹ̀ẹ́ le pè ní kònkarí ànfààní orílẹ̀-èdè wa, ni pé, Ìfọ̀kànbalẹ̀ wà fún gbogbo I.Y.P ní D.R.Y. Gẹ́gẹ́bí Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ṣe máa ńsọ, Àlàkalẹ̀ tí Olódùmarè gbé fún […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ I.Y.P TI BỌ́ SÍNÚ ỌLÁ

Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla máa ń sọ wípé, a kò gbọ́dọ̀ gbàgbé oore ńlá tí Olódùmarè ṣe fún wa ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ( Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y), kí a máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run wa ní gbogbo ìgbà. Ọpẹ́ ló yẹ Olódùmarè fún àánú […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: iypdryTV

Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, sọ fún wa lọ́jọ́ àjọ̀dún ọdún-kéjì tí a ti jáde kúrò nínú Nàìjíríà, èyí tí a ṣe ìkéde-Òmìnira náà ní ogúnjọ́ oṣù bélú, ẹgbàá-ọdún ó lé méjìlélógún, tí àjọ̀dún kéjì náà sì wáyé ní ọjọ́’Rú, ogúnjọ́ oṣù bélú, ẹgbàá-ọdún ó lé mẹ́rinlélógún; wọ́n jẹ́ kó yé wa pé kí a […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÒPIN YÓÒ DÉ BÁ ÌMÚNISÌN

Ní agbára Olódùmarè, ní kété tí àwọn Alákòóso wa bá ti wọlé sí ilé iṣẹ́ ìṣàkóso wa ni ìyàtọ̀ ńlá yóò bẹ̀rẹ̀ nínú ìgbé ayé gbogbo àwa ọmọ Aládé. Kò ní sí àyè fún ẹnìkan láti ma kàwọ́ sókè fẹsẹẹ̀ jan’lẹ̀, níwájú ẹnikẹ́ni bí ẹru mọ́, nítorí ògo oníkálukú á bẹ̀rẹ̀ síi búyọ, kò ní […]

Read more
The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ỌMỌ ÌBÍLẸ̀ YORÙBÁ

Àǹfàànií ńlá ló jẹ́ fún gbogbo àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá pé ní déédéé ìgbà yìí àti ní déédéé àsìkò yìí ni Ọlọ́run Olódùmarè lo Màmá wa Olóyè Ìyá Ààfin Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá fún ìran wa láti jẹ́ kí a dá ara wa mọ̀ gẹ́gẹ́bí  ọmọ Yorùbà nípa ṣíṣí ojú wa sí àwọn ǹkan tí ó wà […]

Read more
Iroyin ojojumo ile yoruba nation dry -yoruba nation is not nigeria.

OLÓRÍ ADELÉ SỌ̀RỌ̀..

Olórí ìṣàkóso-adelé Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), bàbá wa, Mobọ́lájí Ọláwálé Akinọlá Ọmọ́kọrẹ́, sọ ọ̀rọ̀ l’orí àwọn ànfààní ìgbáyégbádùn tí ó ti wà fún ṣíṣe’ṣẹ́ tọ̀, tí àwọn ìṣàkóso-adelé wa bá ti wọlé sínú oríkò-ilé-iṣẹ́ ìṣàkóso ní gbogbo ìpínlẹ̀ wa méjèèje. Wọ́n sọ ọ̀rọ̀ yí lára àwọn ọ̀rọ̀ tí wọ́n bá gbogbo àwa ọmọ-ìbílẹ̀ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ FÚN I.Y.P

Ìbànújẹ́ kò sí fún ẹnikẹ́ni mọ́ ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) pàápàá jùlọ àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) nítorí pé, àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso tí Olódùmarè gbé fún Màmá wa, ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla kò yọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀. Gbogbo àwọn àlùmọ́ọ́nì tí Olódùmarè fi […]

Read more
Iroyin ojojumo ile yoruba nation dry -yoruba nation is not nigeria.

OLÓDÙMARÈ TI KÓ ÌRAN YORÙBÁ YỌ

Ọpẹ́lọpẹ́ Olódùmarè tó wípé ní déédéé ìgbà yí àti ní déédéé àsìkò yí ni kí àwa ìran Yorùbá padà sílé, tó wá gbé ẹni bí ọkàn Rẹ̀ dìde láti jẹ́ iṣẹ́ náà. Màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla, ìyá ìran Yorùbá, kí àánú àti ààbò Olódùmarè máa bá a yín gbé nígbà gbogbo.  Gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌMỌ́TÓTÓ AGBÈGBÈ

Bí a ò kú, ìṣe ò tán Láìsí ìmọ́tótó agbègbè àti àyíká wa, nílé, lóko, lọ́nà ìrìn-àjò, kò sí bí a ṣe máa káwọ́ àrùn tàbí àìsàn. Èyí ló fi dá’ni lójú pé, orílẹ̀-èdè D.R.Y kò ní fi àyè gba ẹnikẹ́ni láti hu ìwà ọ̀bùn tàbí aláìbìkítà fún agbègbè àti àyíká wa.  Ìṣàkóso D.R.Y ní […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

KÒ SÍ ÀWÁWÍ

Màmá Ìran Yorùbá, Ẹni tí Olódùmarè rán sí wa láti ṣe iṣẹ́ ìgbàlà Òmìnira àti ìdándè fún ìlọsíwájú àti Ìdàgbàsókè ọmọ-Yorùbá, Ìyá wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti ṣe ìkìlọ̀ tó lágbára fún gbogbo àwa ojúlówó ọmọ-Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yorùbá (D.R.Y). Wọ́n ní kò sí àwáwí kankan fún I.Y.P […]

Read more