ÌLÚ APANILẸ́KÚN J’AYÉ NÍ ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ
Gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe gbọ́ọ nínú ìròyìn kan pé, àwọn ènìyàn tí ó ní àìsàn ìtọ̀ ṣúgá ni ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, ni wọ́n ti pariwo síta o, pé, àwọn oògùn tí àwọn ńlò fún ìtọ́jú ara wọn, èyí tí wọ́n ń rà ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta àbọ̀ owó wọn, náírà, tẹ́lẹ̀ ti di ọ̀kẹ́ mẹ́sàn […]