Ẹ̀JẸ̀ ỌMỌ YORÙBÁ WÀ LỌ́RÙN NÀÌJÍRÍA
Gbogbo ijọ́ kọ̀ọ̀kan tí ìjọba Agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà bá ṣì jẹgàba sí orí-ilẹ̀ Democratic Republic of the Yoruba, ni wọ́n máa jẹ́jọ́ ẹ̀sùn ẹ̀jẹ̀ ọmọ Yorùbá tí ó nti ọwọ́ wọn ta sílẹ̀. Kò sí Bojú-bojú kankan mọ́; a mọ̀ pé àwọn òyìnbó amúnisìn ni ó nṣe ìdarí nàìjíríà, láti ìta; a dẹ̀ mọ̀ pé àwọn […]