Wọ́n Ṣe Àwárí Òkúta Amúnáwá Lórílẹ̀ Èdè Congo
Tí a bá ń sọ̀rọ̀ orílẹ̀ èdè tí Olódùmarè kẹ́ pẹ̀lú ohun àlùmọ́ọ́nì lórísirísi ní àgbáyé, ipò kíní ni orílẹ̀ èdè Congo wà, ṣé láìpẹ́ yìí ni a rí fọ́nrán kan lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí a ti rí ọkùnrin òyìnbó kan pẹ̀lú àwọn òkúta kan tí ó ń ṣe àyẹ̀wò rẹ̀, bí arákùnrin yìí […]