À ò mọ orúkọ ọkùnrin náà o, ṣùgbọ́n a rí ojú rẹ̀ gedegbe nínú fídíò tí ó ṣe ní orí ẹ̀rọ ayélujára, tí ó nsọ̀rọ̀ ẹranko, ọ̀rọ̀ wèrè, pé kí àwọn Íbò ní Èkó, kí wọ́n dìde, kí wọ́n gbogun ti Ọmọ Yorùbá, kí wọ́n sì ju Yorùbá sínú omi ọ̀sà, kí wọ́n bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ẹni tí ó pè ní Ọba.

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé okùnrin náà nsọ̀rọ̀ láti gbè sí ẹ̀yìn Íbò, bẹ́ẹ̀ náà ni ó sọ pé ọba àkọ́kọ́ ní Èkó, pé Bìní ni ó ti wá, ó wá sọ pé Yorùbá kọ́ ló ni Èkó o, àti pé àwa Yorùbá ò lè sọ pé àwa la ni nkan tí ọkùnrin òmùgọ̀ yí sọ pé kìí ṣe tiwa!

Ohun kan tí ó hàn, gbangba, nínú fídíò yí ni pé, ỌMỌ ÍBÒ TI DÀNÍYÀN, WỌ́N SÌ TI PÈTE ÀTI ṢÍGUN, LÁTI DOJÚKỌ ILẸ̀ YORÙBÁ, PÀTÀKÌ ILÚ ÈKÓ!

A ò mọ orúkọ ọkùnrin yí, ṣùgbọ́n a rí ojú rẹ̀, gedegbe, nínú fídíò ọ̀ún; èyí jẹ́ ẹ̀rí, nígbàtí àsìkò bá tó, pé ó pè fún OGUN láti dojúkọ ilẹ̀ Yorùbá, àti Ọmọ Yorùbá.

Ibi tí ọkùnrin ẹranko náà gọ̀ dé, ó ní tí ó bá ti tó àsìkò, kí àwọn ọmọ Íbò ní Èkó ó finá jó gbogbo Èkó! Àlá tí kò lè ṣẹ! Ara nkan tí a máa nsọ náà nìyẹn, pé àwọn ọmọ Íbò, wọ́n gọ̀ lọ́pọ̀lọ́pọ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ní ìgbéraga WÈRÈ!

Ojú wọn á ja, nígbàtí ìjọba Orílẹ̀-Èdè wa, tí wọ́n ti wà lórí àléfà, tí wọ́n dẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọjọ́ kéjìlá oṣù igbe, ọdún tí a wà nínú rẹ̀ yí – ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rinlélógún – Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), nígbàtí a bá ti wọ inú àwọn oríkò-ilé-iṣẹ́-ìjọba wa gbogbo ní Orílẹ̀-Èdè wa yí!

Gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P), a ò gbọ́dọ̀ gọra wa o! Ká má ṣe rò pé àwọn ẹranko Íbò wọ̀nyí nṣeré ni! Ìyẹn kò túmọ̀ sí pé kí á dààmú o! Ohun tí a nsọ ni pé, a ò gbọ́dọ̀ rò pé Íbò kankan ní ìfẹ́ wa lọ́kàn rárá!

A dẹ̀ gbọ́dọ̀ ṣe àkíyèsí gbogbo ọmọ-àlè Yorùbá, tí wọ́n nsọ̀rọ̀ aláìlọ́gbọ́n, tí ọ̀rọ̀ wọn máà máà gbè sẹ́yìn Íbò nítorí pé “one Nàìjíríà” làwọn nfẹ́ ní ti wọn!

Ohun kan, pàtàkì, tí ó jẹyọ, nínú ọ̀rọ̀ àlùfànṣá tí wèrè ọkunrin kò-jẹ́-Íbò-kò-jẹ́-Bìní yí sọ, ni pé, ó rò pé Nàìjíríà ni a ṣì wa; kò mọ̀ pé Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, èyí tí Èkó wà, ti jáde kúrò lára Nàìjíríà láti ogúnjọ́ oṣù bélú, ẹgbàá ọdún ó lé méjìlélógún, tí a dẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ ìṣejọba-ara-ẹni wa, tí àgbáyé sì mọ̀, láti ọjọ́ kéjìlá osù igbe ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rinlélógún tí a wà nínú rẹ̀ yí, gẹ́gẹ́bí a ṣe mọ̀; ó rò pé ọ̀rọ̀ Nàìjíríà leléyi, ni ẹnu rẹ̀ Rírùn ṣe npọ Ìgbẹ́ ìdí rẹ̀ jáde; bí ẹ bá ṣe ngbọ́ bí ó ṣe nsọ̀rọ̀, ni ẹ ti mọ́ọ mọ irúfẹ́ ìkórira tí àwọn ẹranko Íbò wọ̀nyí ní sí Ìran Yorùbá.

Yoruba Kingdom is the same as Yoruba country and Yoruba nation. All igbo should call their dogs to order. Lagos is a Democratic Republic of the Yoruba State
Ìròyìn Òmìnira Olojoojumọ – Bèrè fún ẹ̀da títí rẹ!

Ó wá sọ tán, ó ní bàbá tó bí Odumegwu Ojukwu, ìyẹn ọ̀gá àwọn Íbò nígbà ayé ogun Biafra lọ́hun, ó ní bàbá tó bi, èyíinì, Louis Ojukwu, pé òun ló mú ìdàgbàsókè wá sí ìlú Èkó: orúkọ Louis Ojukwu tí ó dá yẹn, jẹ́ Ẹ̀rí Nlá pé ìpète-pèrò Ìran Íbò láti gbógun ti Ìran Yorùbá ni gbogbo ọ̀rọ̀ Rírùn tí ọkùnrin tí kò ní ọpọlọ yí nsọ.

Ó tún wá dárúkọ Ibru, pé àwọn tó mú ìdàgbàsókè wá sí Èkó nìyẹn; a ò wá mọ èyí tí ó nsọ nínú àwọn Ibru o, torí àwọn Íbrù pọ̀; a dẹ mọ̀ pé Ibru, ọmọ Delta ní Nàìjíríà ni wọ́n.

Bí ọkùnrin aláìlọ́pọlọ yí ṣe nsọ̀rọ̀, tí ó nyí àwọn Íbò mọ́ Bìní àtí mọ́ Delta, fihàn gbangba pé ara àwọn Biafra ni, torí àwọn biafra ni wọ́n máà nsọ pé ìpínlẹ̀ Edo àti Ìpínlẹ̀ Delta ní Nàìjíríà, pé Biafra ni wọ́n.

Bí àwọn Íbò ẹlẹ́nu gọbọi wọ̀nyí kìí nṣe ímọ àyè wọn nìyẹn. Eegun-apá wọn ni wọ́n fi nronú, ihò-ìdí wọn ni wọ́n dẹ̀ ngbà fi sọ̀rọ̀.

Ọmọ Yorùbá tí ó bá rò pé Íbò kan wà tí ó ní ìfẹ́ òun, ó tan ara rẹ̀ jẹ.

Ìkìlọ̀ dẹ̀ ni eléyi jẹ́ fún gbogbo ọmọ Bìní àti ọmọ Delta tí ó wà nílu Èkó, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), pé kí ẹ máṣe jẹ́ kí àwọn Íbò ó kó tiwọn bá yín o! Ìran Íbò ti dáràn ní orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (D.R.Y), ìyẹn ti dájú!