• Oríkò Ilé-Iṣẹ́, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌYÀWÓ ÀÀRẸ SIERRA-LEONE SỌ̀RỌ̀ SÍTA !

Fatima ni orúkọ̀ ìyàwó Ààrẹ orílẹ̀-èdè Sierra-Leone, ó dẹ̀ sọ pé gẹgẹbí Fatima ni òun ṣe sọ̀rọ̀, òun ò ṣe abẹnugan fún ìjọba Sierra-Leone, òun ò ti ẹ̀ ṣe abẹnugan fún bàálé òun pàápàá, ààrẹ Sierra Leone, ó ní ṣùgbọ́n lórúkọ ara òun ni òun fi nṣọọ́ o, pé, irúfẹ́ òbítíbitì àlùmọ́nì ilẹ̀ tí àwọn […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ JẸ́ KÁ ṢỌ́RA

Ṣebí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni a máa ngba ara wa níyànjú, pé, kí a ṣọ́ra: kó bàá dáa náà ni. Ìkóríta tí a dé yí, gba àfojúsùn gidi: a kò gbọdọ̀ gbàgbé pé àjèjì ni Nàìjíríà jẹ́ lórí ilẹ̀ wa; agbésùnmọ̀mí ni wọ́n; afipá jẹgàba sórí orílẹ̀-èdè tí kìí ṣe tiwọn ni wọ́n, ọ̀daràn ni wọ́n; […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌWÀ ÈKÉ ÀTI ÀGÀBÀGEBÈ BILL GATES

Ọ̀mọ̀wé Vandana Shiva ṣí aṣọ lójú eégún tí wọn ń pè ní Bill Gates àti ọnà àrékérekè tó gbà láti sọ ara rẹ̀ di ògúnná gbòngbò nínú ohun èlò ayárabíàṣá kọ̀mpútà, tí ó sì ń lo ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ láti máa jẹ gaba bí ọlọ́rọ̀ àti gbajúmọ̀ l’ágbàáyé. Obìnrin yìí sọ̀rọ̀ nínú fọ́nrán kan lórí ayélujára […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀṢÀ YORÙBÁ

Gẹ́gẹ́bí a ṣe mọ̀; Ìyá Ìran Yorùbá, ẹni tí Olódùmarè ti rán sí wa gẹ́gẹ́bí Olùgbàlà, ti máa nsọ fún wa, pé, a máa padà sí Orísun wa ni – àṣẹ Ẹlẹ́da wa ni èyí. Kíni orísun wa? Ibi tí a ti ṣàn wá; ìṣèjọba-ara-ẹni wa, gẹ́gẹ́bí Yorùbá, láìsí lábẹ́ ẹnikẹ́ni! Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n […]

Read more
Africa say no to GMO food! Because it will only lead to destruction of black race

ẸNI TÍ Ó BÁ Ń FÚN Ọ NÍ OÚNJẸ NI YÓÒ MÁA ṢE ÀKÓSO AYÉ RẸ

Láìsí àní-àní, ètò ọ̀gbìn ní orílẹ̀ èdè aláwọ̀ dúdú wà ní abẹ́ ìkọlù àti ogun tó lágbára, pàápàá ní orílẹ̀ èdè Kenya. Àwọn  amúnisìn wọ̀nyí kò fẹ́ kí àwọn ènìyàn máa pín irúgbìn ìbílẹ̀ wọn mọ́ nítorí pé, irúgbìn tiwọn ni wọ́n fẹ́ kí àwọn ènìyàn ó máa gbìn. Gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe gbọ́ọ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ONÍṢÒWÒ CHINA TI FẸ́ TA ÀWỌN ILÉ ÌGBAFẸ́ NAIJIRIA O

Àwọn oníṣòwò ọmọ China kan ti gba ìṣàkóso àwọn ilé ìgbafẹ́ ìjọba Nàìjíría tí ó wà ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, wọ́n sì ti ń gbèrò láti tàá, nítorí ìlú agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà kò san owó ìtanràn ẹjọ́  tí àwọn oníṣòwò náà pé Nàìjíríà, èyí tí ìdájọ́ sì ti wáyé ní ẹgbẹ̀wa-ọdún-ó-lé-mọ́kan-lé-lógún, látàrí àdéhùn kan tí ó wà […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌKÌLỌ̀ FÚN GBOGBO Ẹ̀YIN ÀGBẸ̀

Ẹ má ṣe gba irúgbìn GMO lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, ọ̀nà míràn láti pa àwa aláwọ̀ dúdú run ni, àìsàn oríṣiríṣi ni irúgbìn yí yóò fà sí àgọ́ ara ẹnití ó bá jẹẹ́, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹni náà kò ní leè bí ọmọ mọ́, àti wípé, ilẹ̀ tí wọ́n bá gbin irúgbìn yí sí yóò di aṣálẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ÒYÌNBÓ KAN LÁTI ORÍLẸ̀ ÈDÈ RUSSIA LỌ SÍ ÀJÀÒKÚTA

Nínú ìròyìn kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti gbọ́ wípé àwọn ọnímọ̀-ẹ̀rọ bíi mẹ́tàlélógún láti orílẹ̀ èdè Russia ni  wọ́n ti gúnlẹ̀ bàgẹ̀ báyìí o sí ilé iṣẹ́ Àjàòkúta, níbi tí agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà npè ní ìpínlẹ̀ Kogi, ṣùgbọ́n tí apá kan rẹ̀ jẹ́ ti Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN ÌKÀ ṢE ABURÚ FÚN ỌLỌ́PỌLỌ PÍPÉ !

Maxwell ni orúkọ ọkùnrin náà, ní ìlú Zimbabwe, ẹni tí Olódùmarè jogún làákàyè fún ní ti ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ. Ìròhìn lórí ayélujára fi tó wa létí pé Maxwell ti ṣe oríṣiríṣi nkan bí ẹ̀rọ tó ngbé agbára iná mọ̀nọ̀mọ́ná jáde láì lo wáyà, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ṣùgbọ́n nísiìyí, Maxwell wà ní ìlé-ìwòsàn, tìtorí àwọn tí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌ BÌNÍ SỌ BÍ NÀÌJÍRÍÀ ṢE WÁYÉ

Ọmọ Bìní kan lórí ẹ̀rọ ayélujára ló ṣe àlàyé bí ibi tí wọ́n npè ní Nàíjíríà kò ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè, àti pé kíkó tí wọ́n kó Nàìjíríà jọ, gẹ́gẹ́bí ilé-iṣẹ́ ìdókòòwò ni – Royal Niger Company, èyí tí ó di Unilever lóni. Èyí fi hàn wá, gedegbe, bí ó ti ṣe pàtàkì kí á wádi […]

Read more