Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ: OÚNJẸ TÓ DÁRA

Ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), ìgbádùn tí yóò wà fún wa kò lóǹkà, àìríjẹ ti di ohun ìgbàgbé ní ilẹ̀ Yorùbá, oúnjẹ tó dára ní a óò máa jẹ́, nítorí pé ìjọba D.R.Y kò ní fàyè gba ayédèrú oúnjẹ GMO tàbí lílo èròjà tó leè ṣe àkóbá fún […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌBÁSANJỌ́ ṢE AGBÁTẸRÙ WÀRÀ BÍ ỌMỌ-Ọ̀DỌ̀

Àgbà-ìyà Ọbásanjọ́, jóko bí ọmọ̀-ọ̀dọ̀, ẹrú, ní’bi tí àwọn òyìnbó ilé-iṣẹ́ Fan Milk ti ńṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé-iṣẹ́ tuntun láti ṣe wàrà (yógọ́ọ̀tì) ní ilẹ̀ wa, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), ní ìlú Ìbàdàn, ní ìlòdì sí ìjọba-Adelé D.R.Y, torí Ṣèyí Mákindé tí wọ́n dárúkọ rẹ̀ níbẹ̀ kì nṣe D.R.Y l’ó nṣiṣẹ́ fún!Ìyẹn ìkan; ẹ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

LITHIUM: AKÓTILÉTÀ NÀÌJÍRÍÀ NJẸGÀBA

Olódùmarè tó ti ń rán wá lọ́wọ́ látẹ̀yínwá yóò túbọ̀ ràn wá lọ́wọ́ síi láti r’ẹ́yìn àwọn agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà tó ń fipá jẹ gàba lórí ilẹ̀ wa. Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyi, ajẹgàba Nàìjíríà ntan ara wọn jẹ. Èyí tí ó pe’ra rẹ̀ ní Afeez Àlàbí, tí ó sọ pé òun ni Kọmíṣọ́nnà kan ní ibi tí agbésùnmọ̀mí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀKÓJỌPỌ̀ ÌRÒYÌN LÓRÍ BILL GATES [YouTube: African Diaspora News]

(A lo fọ́nrán yí fún ẹ̀kọ́ nìkan, a sì ṣe ìdánimọ̀ fún àwọn tí ó ní ẹ̀tọ́ lórí rẹ̀) A fẹ́ kí ọ̀rọ̀ yí ó yé ẹnìkọ́ọ̀kan wa dáadáa, ìdí nìyí tí a óò fi ṣe àtúpalẹ̀ rẹ̀ ní èdè abínibí wa lẹ́sẹẹsẹ. Gẹ́gẹ́ bí arábìnrin kan ṣe sọ lórí ẹ̀rọ ayélujára pé, ìjọba orílẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ALÁWỌ̀DÚDÚ KÒ JAMỌ́ NKANKAN NÍWÁJÚ ÒYÌNBÓ

Ní òtítọ́ àti ní òdodo, àwọn aláwọ̀funfun, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n mọ̀ pé irọ́ ni àwọn npa, síbẹ̀, wọ́n dúró nínú irọ́ yẹn láti sọ pé aláwọ̀dúdú kò já mọ́’nkankan, wọ́n sì nṣiṣẹ́ tọ̀ọ́ ní ojoojúmọ́! Ẹ̀bi wọn náà dẹ̀ kọ́ọ; ṣébí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìlú ní Áfríkà, nígbà tí wọ́n sọ pé àwọn gba […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ, WÁ DÁHÙN ÌBÉÈRÈ !

Ọmọ ìlú Agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà kan ni a rí fídíò rẹ̀ o, tí ó nbéèrè lọ́wọ́ ìjọba wọn pé kí ó wá ṣe àlàyé, ohun tí kò yé àwọn: tórí ìjọba sọ pé ilé-iṣẹ́ ìfọ’po tí ó wà ní ìlú Warri kò ṣiṣẹ́! Ṣùgbọ́n, ọkùnrin tó sọ̀rọ̀ náa sọ pé àwọn ṣe àkíyèsí pé t’ó bá […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ̀KỌ́ ÒDÌ

Àwa òbí ẹ jẹ́ kí a máa ṣe àbójútó àwọn ọmọ wa dáadáa, nítorí pé àwọn tí wọ́n pe’ra wọn ní alágbára ayé yìí wọ́n fẹ́ dojú ayé bolẹ̀ lòdì sí bí Olódùmarè ṣe dáa ni. Fọ́nrán kan ni a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára tí arábìnrin kan  ń ṣe àlàyé ohun tí ojú rẹ̀ rí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Àǹfààní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá: Orílẹ̀-Èdè Wà Kò Ní Jẹ Gbèsè

Màmá Ìran Yorúbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nfi yé wa pé ìkan nínú àwọn ọ̀nà tí àwọn amúnisìn fi máa nmú àwọn orílẹ̀-èdè ní ẹrú, ni nípa gbèsè jíjẹ. Àwọn ni wọ́n á fa orílẹ̀-èdè náà pé kó wá yáwo; àwọn ni wọ́n a sọ fun bí ó ṣe máa ná owó náà, àti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

OKÒÓ-LÉ-NÍ’GBA BÍLÌỌ̀NÙ DỌ́LÀ FÚN BURKINA FASO

Àwọn ará-ìlú Burkina Faso ti kó owó jọ o! Wọ́n ni àwọn ò gbára lé ìlé-ìfowó-pamọ́ àgbáyé, àwọn ò sì níí yáwó lọ́wọ́ Àjọ-Ayánilówó Agbáyé! Ibrahim Traore, olórí ìlú Burkina Faso fún’ra rẹ̀ ni a gbọ́ pé ó ti sọ eléyi tẹ́lẹ̀ nígbà tí ó dé orí aléfà ìlú náà. Bẹ́ẹ̀ ni ó wá gbé […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ WO BÍ ÌJỌBA ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ ṢE Ń FI ARA NI ARA ÌLÚ

A dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tó kó wa yọ lọ́wọ́ ìnilára àti ìfì’yàjẹni àwọn olóṣèlú ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, ṣé tí ìnira bá ti pọ̀jù kò sí ohun tí ènìyàn kò leè ṣe, èyí ló ṣe okùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ búburú kan tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí ọkùnrin kan tí fẹ́ gba èmi ara rẹ̀ lórí […]

Read more