ÀKÓJỌPỌ̀ ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ LÓRÍ BILL GATES
Tiktok @storiesfromafrica YouTube @universalhertagetnnaija (a lo àwọn fọ́nrán yí fún ẹ̀kọ́ nìkan, a sì ṣe ìdánimọ̀ fún àwọn tí ó ní ẹ̀tọ́ lórí rẹ̀.) Ọ̀rọ̀ yìí dá lórí àwọn ète búburú tí Bill Gates ndáwọ́lé pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ́ ìjọba agbésùnmọ̀mí Naijiria lórí àwọn ohun ọ̀gbin àgbélẹ̀rọ, àwọn amúnisìn yí tún ní èròngbà láti ṣe ikú pa […]