The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀYÈ GBA TÁPÀ Ó Ń  KỌ́’LÉ ÌGUNNU

Ẹ wo Seyi Makinde nínú àwòrán tí ẹ̀rọ ayélujára gbée níbi tí ó ti ń tàn ara rẹ̀ jẹ́ nínú ọ̀rọ̀ ìgbéraga wípé, àwọn wà fún ara ìlú láti sún mọ́ ìjọba, ìyẹn ìjọba agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, nítorí ó yẹ kí o rántí pé, ìwọ àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ tó kù, ẹ kìí ṣe gómìnà Orílè-èdè […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ÀPÀ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ

Orí ni ẹja ti ń bàjẹ́, tí orí ẹja bá ti bàjẹ́, kò sí àní-àní, gbogbo ẹja náà ló ti bàjẹ́. Ìròyìn tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni pé, bílíọ̀nù mẹ́fà àbọ̀ náírà ni wọ́n lò láti  tún ilé ìgbàfẹ́  kan ṣe ní ìpínlẹ̀ Ìṣèjọba Ọ̀yọ́ (old Ọ̀yọ́ Empire), ọ̀kan lára àwọn Ìpínlẹ̀ wa ní orílẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌWÀ ÒPÈ GBÁÀ

Ọmọbìnrin kan tí a rí fídíò rẹ lórí ayélujára X, ló sì fẹ́ má hùwà òpè nípa kí ká Yorùbá mọ Nàìjíríà. Èyí jẹ́ ìwà òpè gbáà tí ọmọbìnrin nà hù, nítorí Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) kò sì lára Nàìjíríà mọ láti ìgbà tí ati ṣe ìkéde òmìnira wa, ni ogúnjọ́ oṣù Bélú, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ Ẹ̀YÁWÓ FÚN ÀWỌN ONÍṢÒWÒ

Nígbà gbogbo ní àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹlẹ́dàá wa tó rántí wa sí rere, tó sì gbà wá lọ́wọ́ àwọn amúnisìn nípasẹ̀ màmá onínúure, ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla tó rán sí wa. Àyípadà ọ̀tun ti de bá gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN JÀGÙDÀ BABA OLÈ

Afẹ́fẹ́ ti fẹ́, a ti ri ibi tí adìyẹ fi nṣe gá. Ọkùnrin ọ̀daràn kan, Jẹ̀lílì Alégẹ tó pe ara rẹ̀ ní alága ìjọba ìbílẹ̀ Àlímọ̀ṣọ́ ní ipinlẹ̀ Èkó gbé fónrán kan jáde lórí ayélujára “X,” láti sọ̀rọ̀ nípa àwọn arúfin tó npe ara won ní ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó ní Orílẹ̀ Èdè […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ KÉÉKÈÈKÉ AGBÉNIPA YỌ KÍNDÌNRÍN TÀ

Ẹ wò bí Nàìjíríà ṣe sọ àwọn ọmọ kéékèèké dà, àwọn ọmọ tí kò tíì pé ogún ọdún tí wọn máa ń gbé àwọn ènìyàn lọ pa, tí wọ́n máa yọ kíndìnrín wọn tà fún àwọn tí wọ́n máa tún tà fún àwọn alágbáyé tí wọ́n ń tọ́jú kíndìnrín pamọ́.  Àwọn ọmọdé wọ̀nyí a máa […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌ YORÙBÁ Ẹ FURA!

Ìròyìn kan ní a rí lórí ayélujára tí o un sọ nípa bí àwọn ọmọ ìgbò ṣe ún kó ara wọn ni ọ̀pọ̀ yanturu wá sí ìpínlẹ̀ Èkó ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùba Democratic Republic of the Yorùba(D.R.Y).  Kíni kí a ti pe irú ìwà àìbìkítà yi? Nítorí ojú wọn kòfọ́ bẹ́ẹ̀ni etí wọn […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌWỌ́ TẸ ÌYÀWÓ ILÉ KAN TÍ Ó GBÉ ỌMỌ SỌNÙ

Ìyàwó ilé kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Barkisu Sulaiman ní ọwọ́ tẹ̀ ní, Karaworo-Lokoja lórí wípé ó sọ ọmọ tuntun jòjòló, ọmọ òòjọ́ rẹ̀ sínú odò. Obìnrin Barkisu yìí ni a gbọ́ pé, o ni oyún ọmọ náà fún ọmọ ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀ tì ń ṣáàrẹ̀, ìgbà tí ọkunrin ọmọ ọ̀dọ̀ náà gbọ́ pé […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: YORÙBÁ KÍKỌ SÍLẸ̀

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y), à ò ní sọ èdè ẹrú, èdè Yorùbá pọ́ńbélé ni a óò máa sọ bẹ́ẹ̀ sì ni kíkọsílẹ̀ rẹ̀ gbọ́dọ̀ ni àwọn àmì tó yẹ lórí tàbí nìdí álífábẹ́ẹ́tì kọ̀ọ̀kan èyí yóò mú kó rọrùn fún òǹkàwé láti pe ọ̀rọ̀ náà bí […]

Read more