Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

D.R.Y KÒ DÚRÓ SÍNÚ ÒKÙNKÙN MỌ́

Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ni orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) ti wà nínú òkùnkùn látàrí ìwà àti ìṣe àwọn tí wọ́n pe’ra wọn ní adarí tàbí aṣíwájú pàápàá àwọn olóṣèlú ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà. Wọn ò jẹ́ kí a mọ púpọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tó ń ṣẹlẹ̀ ní orí ilẹ̀ wa. Wọ́n […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: IPÒ YÍYÀN

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ wípé lórí òtítọ́ àti òdodo ni a gbé ìpìlẹ̀ wa lé, nítorí náà, kò ní sí ojúṣàájú nínú gbogbo ohun tí a bá ń ṣe, pàápàá ní àkókò yíyan adarí tàbí aṣojú, yálà ní ilé iṣẹ́ tàbí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀṢÍRÍ ÌKỌ̀KỌ̀ ÀWỌN AMÚNISÌN

Ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yí, ó kọjá à fẹnu sọ. Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, tí máa ń fi yé wa láti àtẹ̀yìnwá pé, orílẹ̀-èdè ni àwa Ìran Yorùbá àti pé Èdè ni a fi ń júwe orílẹ̀-èdè; bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ti máa ń fi yé wa pé, ibi tí wọ́n […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÒMÌNIRA TÍTÍ AYÉ

Ní gbogbo ìgbà ni àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹlẹ́dàá wa fún oore ńlá tó ṣe fún wa, fún òmìnira àìlópin èyí tó ti ọwọ́ màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla ṣe fún àwa ọmọ Aládé. Bẹ̀rẹ̀ láti ogúnjọ́ oṣù Bélú ẹgbàáọdúnóléméjìlélógún tí a kéde òmìnira orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ALÁBỌ̀DÈ L’ỌBA ILẸ̀ YORÙBÁ.

Láti ìgbà láíláí ni àwọn Ọba ilẹ̀ Yorùbá ti jẹ́ ọ̀dàlẹ̀, ìkà àti alábọ̀dè sí ìran Yorùbá, kí àwọn amúnisìn tóó dé ni wọ́n tí ń kó ọmọ Yorùbá l’ẹ́rú àti lẹ́rù, ìdí nìyí tí àwọn aláwọ̀ funfun ṣe fi ńkan tí ò tó ńkan kó àwọn ọmọ Yorùbà lẹ́rú. Ọgbọọgbán ni àwọn amúnisìn lò […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

IRỌ́ LÓRÍ IRỌ́ NI NÀÌJÍRÍÀ

Èdùmàrè máṣe jẹ́ kí á fi ìpìlẹ̀ ayé wa lé orí irọ́! Tí kìí bá ṣe pé Ọlọ́run Olódùmarè tí ó gba Ìran Yorùbá sílẹ̀ nípasẹ̀ iṣẹ́ ribiribi tí Ó lo Ìyá wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá fún, Kínni à bá ma wí?  Ẹ jẹ́ kí á wo iye ọdún tí a ti wà nínú Irọ́ kàbìtì […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌMÓJÚTÓ ARÁ-ÌLÚ

Ìṣètò Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) wà fún ìmójútó ará-ìlú. Èyí ni pé kò sí ìjìyà mọ́ fún ọmọ Yorùbá. Orílẹ̀-Èdè wa yíò mójútó gbogbo ohun tí a máa fi ní ìgbáyé-gbádùn, a ò sì ní máa sun ẹkún àìríjẹ, àìrímu, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Gẹ́gẹ́bí Àlàkalẹ̀ tí Olódùmarè […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

A Ò GBỌDỌ̀ GBÀGBÉ OORE OLÓDÙMARÈ

Ní àìpẹ́ yí ni Màmá wa, Iyá Ìran YORÙBÁ , Ìyá Wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, tún rán’wa léti pé, a ò gbọdọ̀ gbàgbé oore tí Olódùmarè ṣe fún Ìran wa – nítorí ohun ti ojú wa ti rí kò rú’jú mọ́, ní àkókò yí, pé ìfẹ́ àti ète àwọn ọ̀tá ni pé kí Ìran Yorùbá ó […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

KÒ SÍ ÀJÒJÌ TÓ LÈ FI ỌWỌ́ LALẸ̀ FÚN I.Y.P

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) gbèdéke yóò wà fún àwọn àjòjì tó bá wù láti gbé ní orílẹ̀ èdè wa. Bí àpẹẹrẹ, àjòjì kò leè jẹ adarí ní ilé iṣẹ́ kankan ní ilẹ̀ Yorùbá, kò sí ààyè fún àjòjì láti kó ọmọ Yorùbá lẹ́rú mọ́, àjòjì kò ní […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

KÍ A ṢÁÀ MÁ DÚPẸ́ LÓ TỌ́

Gẹ́gẹ́ bí orin tí a má ń kọ nígbà dé ìgbà ni ilẹ̀ Yorùbá, wípé:Ká sá máa dúpẹ́ ló tọ́, Ká sá máa dúpẹ́ ló tọ́,Ọrọ wá ó gbà ẹjọ́ wẹ́wẹ́, A fi ká sá máa dúpẹ́ ló tọ́. Ní ìkòríta tí a dé bá yí, bí màmá wa Ìyá Ààfin Modupẹ́ọla Onitiri-Abiọ́la ṣe bá […]

Read more