ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ỌGBỌ́N ÀTINÚDÁ WA
Láti ìgbà ìwásẹ̀ ni àwọn babańlá wa ti ń lo ọgbọ́n àtinúdá wọn láti mú ayé rọrùn fún ara wọn. Ọgbọ́n nípa aṣọ wíwọ̀, oge ṣíṣe, iṣẹ́ ọnà, ìkòkò mímọ, ilà kíkọ, ìlù lílù, ère gbígbẹ́, apẹ̀rẹ̀ hínhun, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. A ma ṣe àwárí ara wa ní kété tí àwọn Alákóso wa bá ti […]