ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: I.Y.P YÓÒ NÍ Ẹ̀TỌ́ SÍ OJÚLÓWÓ NÍ D.R.Y
Gẹ́gẹ́bí Màmá wa, Olóyè ìyá-ààfin Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá MOA ṣe ma nsọ wípé lẹ́yìn Ọlọ́run Olódùmarè, Yorùbá ni àkọ́kọ́. Nínú ohun gbogbo tí ó bá ti njáde ní orílẹ̀ èdè wa, Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá, I.Y.P ni a kọ́kọ́ ní ẹ̀tọ́ si. Nínú ètò ọ̀gbìn Yorùbá ni àkọ́kọ́, ohun gbogbo tí a bá nṣe […]