ÀJỌYỌ̀ ỌPẸ́
Àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ màmá wa, ìyá ìran Yorùbá, Ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ṣe fún ìran Yorùbá, Olódùmarè lo màmá wa láti kó wa jáde kúrò nínú oko ẹrú […]