ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: OWÓ ÒṢÌṢẸ́ NÍ D.R.Y
Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) jẹ́ orílẹ̀-èdè àwọn ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P), tí ìṣe-rere gbogbo I.Y.P jẹ lógún. Ìkan gbòógì lára ohun tí D.R.Y dúró lé, ni pé, láyé, ìyà kò tún jẹ ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá mọ́. Olódùmarè kẹ́ ìran Yorùbá, púpọ̀púpọ̀, bí ó ṣe kẹ́ […]