Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌWỌ́ TI TẸ KUNLE POLLY

A rí ìròyìn kan tí ó jáde lori ẹ̀rọ ayélujára pe, ọwọ́ àwọn agbófinró tí ìlú arufin Nàìjíríà tí wọ́n taku sí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ní ìpínlẹ̀ Ogun, ti tẹ ògbóńtagìrì elẹ́gbẹ́ òkùnkùn kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Adekunle Adebanjo, tí wọ́n máa ń pè ní “Kunle Polly“, fún pé ó lọ́wọ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AGBÉSÙNMỌ̀MÍ S’ỌṢẸ́ FÚN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ

Ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sanusi Ango Gyaza ẹnití ó ti f’ìgbà kan jẹ́ alága ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ní ìjọba ìbílẹ̀ Kankia ní ìlú agbésùnmọ̀mí Nàíjíríà, tí ó sì tún jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina wọn lọ́hun, ni a gbọ́ pé àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe ìkọlù sí ilé rẹ̀ tí wọ́n sì ṣ’ekú […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

TINUBU ÀTI ÌGBÌMỌ̀ ỌRỌ̀ AJÉ RẸ̀ Ń PA OWÓ EPO ÌLÚ SÍ ÀPÒ ARA WỌN

Ní ìlú tí ó fi ẹ̀gbẹ̀ ti Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ìlú agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, ọ̀kan lára àwọn omọ ẹgbẹ ìgbìmọ̀ ọrọ̀ ajé ti ààrẹ wọn, Tinubu gbékalẹ̀ sọ nípa bí wọ́n ṣe ń ṣe àgbéwọlé epo lati ìlú Malta, Russia ní ọ̀nà àìtọ́ lọ sí ìlú wọn, Naijiria. Olórí ìlú Naíiìrìa. Ọ̀gbẹ́ni Bọ́lá Tinubu […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÒGO ỌLỌ́RUN NÍNÚ ỌMỌ YORÙBÁ

Nínú gbogbo ọ̀rọ̀ tí Ìránṣẹ́ Olódùmarè, Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, máa nbá wa sọ, gbólóhùn kan sábà máa nwáyé: èyíinì ni “Ògo Ọlọ́run.” Wọ́n sábà máa nsọ fún wa pé, “Ní dédé àsìkò yí, ní dédé ìgbà yí, Ọlọ́run fẹ́ kí a pàdà sí Orísun wa, kí á kúrò ní oko ẹrú, kí á […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

BILL GATES, ÒṢÌṢẸ́ ÀṢÌTÁÁNÌ

Nígbàtí a bá ngbọ́ pé àwọn òyìnbó amúnìsìn fẹ́ pa ọmọ aráyé, àwọn kan le má fẹ́ gbàgbọ́; ṣùgbọ́n òtítọ́ gedegbe ni ọ̀rọ̀ yí. Ìba àwọn tó bá kù, tí wọn ò pa, wọ́n fẹ́ ṣe ètò kí wọ́n máṣe lè gbé irúfẹ́ ìgbé-ayé tí wọ́n fẹ́ gbé, ṣùgbọ́n kí ó jẹ́ pe àwọn tí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ KÍYÈSÁRA!

Kí Olódùmarè kí ó má jẹ̀ẹ́ kí a fi ọwọ́ ara wa se ara wa ò. Nínú ìròyìn kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti rí arábìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tucker Carlson tí ó sì ń ṣe àlàyé àwọn àìsàn tí ó ń sẹ́yọ látàrí àwọn nǹkan jíjẹ tí kò […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

DAPO ABIODUN Ń FI ÀRÉKÉREKÈ TA ILẸ̀ D.R.Y.

Ìròyìn kan tí ó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára ni ọjọ́ kẹẹ́dógún oṣù Ògún tí a wà nínú rẹ̀ yìí, ni a ti rí àwòrán Ọ̀gbẹ́ni Dapo Abiodun, tí ó jẹ́ aṣojú ìlú Nàìjíríà, tí ó ń jẹ gàba lórí ilẹ̀ Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ati olórí àwọn jagunjagun orí omi, Emmanuel Ogalla, tí wọ́n bọ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FARANSÉ KÒ ṢE WÁ LÓORE – Traore sọ bẹ́ẹ̀

Ààrẹ ìlú Burkina Faso, Akọgun Ibrahim Traore, sọ pé láti ọdún mẹ́ta-lé-lọgọ́ta tí orílẹ̀-èdè àwọn ti ngba “ìrànlọ́wọ́” láti ọ̀dọ̀ àwọn Faransé, kò sí ìdàgbàsókè kankan tí ó mú bá wọn; nítorí èyí, ó ní àwọn ò lè kú tí àwọn ò bá gba ìrànlọ́wọ́ Faransé mọ́, kàkà bẹ́ẹ̀, nṣe ló máa jẹ́ kí àwọn […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌTỌ́JÚ ARÚGBÓ

Ní Orílẹ̀-Èdè Olóminira Tiwantiwa ti Yorùbá, Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, máa nsọ fún wa pé ìtọ́jú tó péye máa wà fún gbogbo ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá, látàrí bí ìlú ṣe máa dára tó, bíó tilẹ̀ jẹ́ pé a máa ṣe iṣẹ́ tọ̀ọ́ ni, ṣùgbọ́n fún àwọn arúgbó wa, ìjọba tún ní ètò bí ọjọ́ ogbó […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ỌMỌ-ẸGBẸ́ APC NI ÒPÒNÚ ÌGBÒ ÀNÁ

Láìpẹ́ yí ni a  mú ìròhìn tó wa létí bí wèrè ọkùnrin kò jẹ́ Íbò kò jẹ́ Bìní kan ṣe npè fún ogun, pé kí àwọn Ibò tó wà ní Èkó ó dojú ìjà kọ’ra wọn láìṣe àwa. Ìròhìn tí a tún rí lórí ẹ̀rọ ayélujára X, fi hàn pé ọmọ-ẹgbẹ́ òṣèlú APC, ẹgbẹ́ ààrẹ […]

Read more