HÀÀ! Ẹ WO NKAN TÍ ỌMỌ YORÙBÁ DÀ!
Ó ṣeni láanú pé ọmọ Yorùbá ti wá di ẹni tí a nkà mọ́ olè àti ajínigbé, látarí ìlú burúkú, Nàìjíríà, tí wọ́n ba ilẹ̀ wa jẹ́ láti ìgbà tí òyínbó amúnisìn ti so wá papọ̀ mọ́ oríṣiriṣi ìran míràn, ṣùgbọ́n tí a ti wá jáde láti ogúnjọ́ oṣù bélú, ẹgbàá ọdún ó lé méjìlélógún, […]