TINUBU ÀTI ỌMỌ RẸ̀ KỌJÁ ÀYÈ WỌN
A rí ìròyìn kan kà lórí ẹ̀rọ ayélujára X, bí Seyi, ọmọ Tinubu, ṣe ní ilé iṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀rẹ̀ rẹ̀ Lebanese, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́, Ronald Chagoury. Èyí kìí ṣe èèwọ̀. Ṣùgbọ́n ọmọ Chagoury yí tún ní ilé-iṣẹ́ kan tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Hightech Construction, èyí tí ìjọba Agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà tó njẹgàba lórí ilẹ̀ […]