AGBÉRAGA T’Ó PE’RA RẸ̀ L’Ọ́BA
Nínú ohun gbogbo, ẹ jẹ́ kí a máa bẹ̀rù Ọlọ́run, àwọn tí ìrẹ̀ wọ́n yó tán, tó wá ní kí wọ́n fi kété tú ìfun òun, ni ọ̀rọ̀ àwọn tí a fẹ́ sun jẹ, tí wọ́n wá fi epo para, wọ́n bá lọ jókòó ní ẹ̀yìn ààrò; òun ní ọ̀rọ̀ àwọn agbéraga tí wọ́n pé’ra wọn […]