ÀWỌN AKÉKỌ̀Ọ́ ILÉ ÌWÉ GÍGA FÁSITÌ ÌBÀDÀN FI Ẹ̀HÓNÚ WỌN HÀN
Ìròyìn kan jáde pé àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Fásitì Ìbàdàn ti bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn míràn, látàrí àfikún owó ile ìwè wọn. Ilé ẹ̀kọ́ Fásitì yí wà ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá(Democratic Republic of the Yorùbá, DRY) ti ìlú agbèsùnmọ̀mí Naijiria ń fi ipá jẹgàba lórí rẹ̀, ìjẹgàba àwọn agbésùnmọ̀mí náà ló fa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ bí […]