ÌṢÀKÓSO ÀLÙMỌ́NÌ ILẸ̀
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí òye kò yé, ni wọ́n ti béèrè pé “kí la máa jẹ,” “kí la máà mu,” àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ní Orílẹ̀-Èdè wa. Ọ̀rọ̀ yí kò rújú rárá; Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nsọọ́, láti ìgbà dé ìgbà, pé nísiìyí tí a ti polongo ìṣèjọba-ara-ẹni wa, tí a dẹ̀ ti ṣe […]