ỌBÁSANJỌ́ ṢE AGBÁTẸRÙ WÀRÀ BÍ ỌMỌ-Ọ̀DỌ̀
Àgbà-ìyà Ọbásanjọ́, jóko bí ọmọ̀-ọ̀dọ̀, ẹrú, ní’bi tí àwọn òyìnbó ilé-iṣẹ́ Fan Milk ti ńṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé-iṣẹ́ tuntun láti ṣe wàrà (yógọ́ọ̀tì) ní ilẹ̀ wa, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), ní ìlú Ìbàdàn, ní ìlòdì sí ìjọba-Adelé D.R.Y, torí Ṣèyí Mákindé tí wọ́n dárúkọ rẹ̀ níbẹ̀ kì nṣe D.R.Y l’ó nṣiṣẹ́ fún!Ìyẹn ìkan; ẹ […]