ÌWÀ ÌBÀJẸ́ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ
Ìròyìn tí a gbọ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára X, ìkànnì @dammiedammie35, nípa àwọn ọlọ́pa ajẹgàba Nàìjíríà tí wọ́n fi àìlẹ́tọ́ dúró sí Surulere, ní ìpínlẹ̀ Èkó, Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y, sọ pé wọ́n fi ipá mú àwọn ọ̀dọ́ mẹ́ta kan láti fún wọn ní mílíọ̀nù kan owó náírà torí pé wọn ò mú ìwé […]