EWÉ àti EGBÒ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ ṢE PÀTÀKÌ
Ní àti ayébáyé ni àwọn babanlá wa ní ilẹ̀ Yorùbá ti mọ̀ nípa ìlò ewé, egbò, èso, irúgbìn èso, àti oríṣiríṣi ohun ní àyíká wa láti ṣe ètò ìwòsàn ara fún ọmọ Yorùbá. Olódùmarè, nípa ọgbọ́n inú àti ìtọnà, àti ìwádi àwọn baba wa, ni ó fi nkan wọ̀n yí hàn wọ́n. Èyí túmọ̀ sí […]