ỌBA ÍLẸ̀ YORÙBÁ NÍGBÀTÍ AMÚNISÌN DÉ
Ilẹ̀ Yorùbá jẹ̀ orílẹ̀ èdè olómìnira aṣèjọba ara ẹni láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ wa. Nígbàtí àwọn òyìnbó amúnisìn wọlé dé, wọ́n bá wa pé ọba àti àwọn ìjòyè ló ńṣe kòkárí ìṣàkóso ìṣèjọba nígbà náà. Àrékérekè ati ẹ̀tàn ni àwọn aláwọ̀ funfun yìí lò láti sọ ara wọn di amùnisìn lóri ìran Yoruba. Àwọn òyìnbó yí […]