ÌTÀNJẸ LÁSÁN NI ABẸ́RẸ́ COVID 19
Ọkùnrin òyìnbó kan fi àìdùnnú rẹ̀ hàn nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára covid 19, ó wí pé, ìdí tí àwọn ìjọba wọn fi mú àwọn ènìyàn ni dandan láti gba abẹ́rẹ́ ọ̀hún kò yé òun rárá nítorí pé kò sí iṣẹ́ kankan tí ó ṣe láti dènà àìsàn náà. Ó tẹ̀síwájú nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé, gẹ́gẹ́ bí […]