• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Pàtàkì Àgbékalẹ̀ (Blueprint) Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá (D.R.Y)

Ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ ìgbà ni a ti gbọ́ l’ati ẹnu Màmá, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, nípa Àgbéka’lẹ̀ (tí a tún le pè ní Àlàka’lẹ̀) fún Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá. Ẹlòmíràn nínú wa lè máa rò wípé, Èwo tún ni “blueprint”? Nít’orí bóyá a ò gbọ rí wípé nkankan wà t’ó tún njẹ́ “Blueprint” (tàbí, Àlàka’lẹ̀ Ìgbéka’lẹ̀) fún orílẹ̀-èdè. […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Susan Rice Purọ́ Nínú Ìwé Rẹ̀ Nípa Ikú MKO Abíọ́lá

Ní’gbà tí Olóyè MKO Abíọ́lá kú, ní ọjọ́ kéje, oṣù kéje, ọdún 1998, a mọ̀ wípé wọ́n fun ní tea mu, Susan Rice, òṣ’iṣẹ́ fún ìjọba America sì pẹ̀lú àwọn tí wọn jọ wa ní’bẹ̀, pẹ̀lú àwọn ìjọba ol’ógun Nigeria. Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Má Ṣe Gb’ara Lé Ọmọ Íbò, Ẹni ibi Ọ̀dàlẹ̀ Ìran Níwọ̀n

Àfi ẹnití kò bá mọ ọṣẹ́ tí àwọn ọmọ Íbò tí ṣe sí àwọn ẹ̀yà míràn ní ibi tí àwọn òyìnbó amúnisìn kó papọ̀ ní’jọ́ náà l’ọhún, tí wọ́n pè ní Nigeria, l’ó máa rò wípé ènìyàn gidi ni àwọn ìran Íbò jẹ́. Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí […]

Read more
Ẹ̀kún Rẹ́rẹ́ Ọ̀rọ̀ Olórí Adelé Ní Àyájọ́ June 12

Ẹ̀kún Rẹ́rẹ́ Ọ̀rọ̀ Olórí Adelé Ní Àyájọ́ June 12

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Olori Adele Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, Ọgbeni Mobọlaji Ọlawale Akinọla Ọmọkore A dúpẹ́ l’ọwọ́ Ọlọ́run Olódùmarè, fún Àánú àti Ààbò Rẹ̀, l’orí gbogbo àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá. […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ìpèsè Omi Ẹ̀rọ Ní Ilẹ̀ Yorùbá Ní Ọgọ́ta Ọdún S’ẹhìn

Ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ ọmọ Yorùbá, l’oní, ni kò mọ̀ wípé, ní ìgbà kan rí, nígbàtí Yorùbá ṣì nṣe àkóso ara wọn bí ó ti’lẹ̀ jẹ́ wípé Nàìjíríyà ṣì mbá ìjọba àpapọ̀ lọ ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ wípé, Yorùbá wà ní àyè ara rẹ̀; nṣe ni ìpèsè omi ẹ̀rọ t’ó mọ́ gaara wà káàkiri ilẹ̀ Yorùbá. Títí dé […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ọmọ-Alade Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá Ṣe Àlàyé Nípa Ìbò Dídì Ní D.R.Y

Ẹnik’ẹni ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (D.R.Y) tí ó bá fẹ́ gbé àpótí Ìbò nígbàkúgbà, kí ó mọ̀ báyi wípé kò ní ọ̀rọ̀ owó nínú o. Kò sí wípé iye owó bái ni o máa fi gba ìwé pé o ní’fẹ́ àti gbé’gbá ìbò, rárá o! Ẹnik’ẹni tí ó bá sì tìtorí ẹni t’ó […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá (MOA) S’ọ̀rọ̀ Ní Àyájọ́ June 12

Ìránṣẹ́ Ọlọ́run Alààyè sí Àwa Ìran Yorùbá, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, sọ gbẹgudu ọ̀rọ̀ fún àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ti Oríl-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ní ọjọ́ ‘rú, ọjọ́ kéjìlá, oṣù kẹ́fà, odún 2024, tí ó jẹ́ àyájọ́ ọjọ́ tí Olóògbé MKO Abíọ́lá tí wọ́n já’wé olúborí nínú ìdíje fún ipò ààrẹ ní ìlú Nigeria nígbànáà, ṣùgbọ́n […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àwọn Òyìnbó, Aláyébàjẹ́ Ni Wọ́n

Èyí kìí ṣe ọ̀rọ̀ ìkórira òyìnbó, ṣùgbọn, tí a kò bá ní tan ara wa jẹ, a níl’ati jẹ́ kí a mọ oríṣiríṣi ohun ibi tí àwọn òyìnbó wọ̀nyí nṣe sí ọmọ ènìyàn àti sí gbogbo àyé. Ní àípẹ́ yi ni òṣìṣẹ́ ètò ìwòsan kan tí òun fún’ra rẹ̀ jẹ́ òyìnbó, ni ó sọ, tí […]

Read more