ÀWỌN ÒYÌNBÓ SỌ PÉ KÒ SÍ Ọ̀RÀN NÍNÚ BÍBÁ ỌMỌDÉ LÒPỌ̀! Ẹ GBÀ WÁ O!
Oríṣiríṣi ń kan la máa ngbọ́ tí àwọn òyìnbó máa nsọ. Kí á má sọ pé ó ṣe jẹ́ lórí ọ̀rọ̀ òyínbó ni gbogbo ń kan tí a ń sọ wá ndálé? Ẹbi wá kọ́ọ, ìrònú-ẹrú tí wọ́n ti kó sí orí ọ̀pọ̀lọpọ̀ aláwọ̀dúdú ló ń jẹ́ kí á pe àkíyèsí wa sí àwọn nǹkan […]