• Oríkò Ilé-Iṣẹ́, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ọ̀RỌ̀ OWÓ NÍNÁ

Ní àìpẹ́ yí ni Ìyá Wa, Olùgbàlà tí Olódùmarè rán sí Ìran Yorùbá, Màmá, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá bá gbogbo ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yorùbá (D.R.Y), sọ̀rọ̀; wọ́n bá wa sọ gbólóhùn díẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ owó àwọn aríremáṣe Nàìjíríà, àti bí àwa D.R.Y kò ṣe ní ohunkóhun láti ṣe […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: GBOGBO I.Y.P NI YÓÒ NÍ IṢẸ́ LỌ́WỌ́

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ni a ó ní iṣẹ́ lọ́wọ́ nítorí pé iṣẹ́ yóò pọ̀ yanturu ní orílẹ̀ èdè D.R.Y. Gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe mọ̀ wípé, iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, ẹ̀dá tí kò bá sì […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÈPÈ ÀTI ÈGÚN FÚN ÀJÈJÌ ANINILÁRA

Màmá Ìran Yorùbá, Olùgbàlà tí Olódùmarè rán sí àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, jẹ́ kó yé àwa ojúlówó Ọmọ-Ìbílẹ̀-Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) wípé a ní láti rọ òjò èpè àti ègún lé gbogbo àwọn àjèjì tí ó wà káàkiri ilẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ọ̀KAN NI GBOGBO ÀWA I.Y.P TI D.R.Y

Ìkan nínú ọ̀rọ̀ tó ṣe gbòógì tó pè fún àkíyèsí, tí màmá wa Olóyè Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá sọ jẹ́ ọ̀rọ̀ pàtàkì  “Lẹ́yìn Ọlọ́run Olódùmarè Yorùbá ni Àkọ́kọ́“. Màmá wá MOA tẹnu mọ fún àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (lndigenous Yorùbá People, l.Y.P) tí Democratic Republic of the Yorùbá (D.R.Y), wípé “Ọ̀KAN” ni wá bí òṣùṣù […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ỌGBỌ́N ÀTINÚDÁ WA

Láti ìgbà ìwásẹ̀ ni àwọn babańlá wa ti ń lo ọgbọ́n àtinúdá wọn láti mú ayé rọrùn fún ara wọn. Ọgbọ́n nípa aṣọ wíwọ̀, oge ṣíṣe, iṣẹ́ ọnà, ìkòkò mímọ, ilà kíkọ, ìlù lílù, ère gbígbẹ́, apẹ̀rẹ̀ hínhun, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. A ma ṣe àwárí ara wa ní kété tí àwọn Alákóso wa bá ti […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌTÚSÍLẸ̀ FÚN GBOGBO ẸLẸ́WỌ̀N

Màmá wa, Ìránṣẹ́-Olódùmarè sí Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, tún ti rán àwa Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) létí, ní àìpẹ́ yí, pé, gẹ́gẹ́bí àwọn ṣe sọ fún wa ní ìgbà kan rí, wọ́n ní kété tí àwọn Alákoso-Adelé wa, bá ti wọ inú oríkò-ilé-iṣẹ́-ìṣàkóso wa […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ẸWÀ ÈDÈ YORÙBÁ

Orílẹ̀ èdè tó bá ti sọ èdè rẹ̀ nú yóò parun, ká dúpẹ́ fún Olódùmarè tí ò jẹ́ kí ìran Yorùbá parun. Títí láé ni àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tó rán ẹni bí ọkàn Rẹ̀ sí wa, màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla láti mọ ìtúmọ̀ èdè tí ò lẹ́̀ kí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN AMÚNISÌN Ń LO ÀWỌN GBAJÚMỌ̀ ILẸ̀ YORÙBÁ

Tí ò bá sí olè ilé, olè ìta kò le jà! Ọ̀rọ̀ yí ló dífá fún bí àwọn amúnisìn ṣe lo àwọn tí wọ́n pe’ra wọn ní gbajúmọ̀ ilẹ̀ Yorùbá láti máa tako òmìnira ilẹ̀ Yorùbá. Wọ́n kọ́kọ́ da àwọn gbajúmọ̀ yí ní ọpọlọ rú, wọn jẹ́ kí wọ́n rò wípé ohun gbogbo tó bá […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌTỌ́JÚ FÚN ỌMỌ ÒRUKÀN

Ànfààní tí ó wà fún Ọmọ-Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) kò lónkà! Tí a bá ní kí a máa wòó lọ́kan-ò-jọ̀kan, ọpẹ́ lóyẹ kí á máa dá lọ́wọ́ Olódùmarè tí Ó gbé Àlàkalẹ̀ Rere fún Ìran Ọmọ Yorùbá, tí Ó sì tún wá jínkí wa pẹ̀lú Olùgbàlà, […]

Read more