The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: OWÓ ÒṢÌṢẸ́ NÍ D.R.Y

Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) jẹ́ orílẹ̀-èdè àwọn ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P), tí ìṣe-rere gbogbo I.Y.P jẹ lógún. Ìkan gbòógì lára ohun tí D.R.Y dúró lé, ni pé, láyé, ìyà kò tún jẹ ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá mọ́. Olódùmarè kẹ́ ìran Yorùbá, púpọ̀púpọ̀, bí ó ṣe kẹ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AJẸGÀBA NFI ÌYÀ JẸ ARÁ ÌLÚ

Tí a bá nsọ pé ètò-amúnisìn ni ibi tí wọ́n npè ní nàìjíríà; tí a bá nsọ pé ìkà ni wọ́n, tí a bá nsọ pé ìparun ọmọ Yorùbá ni wọ́n nwá, a mọ bó ṣe nlọ o, a sì mọ ìdí tí a fi sọ bẹ́ẹ̀! Ti Yorùbá ló kàn wá o, ìdí nìyẹn […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ JẸ́ KÍ A GBỌ́RÀN

Nínú ọ̀rọ̀ Màmá wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá-Ààfin) sí àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.YP) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), ní àìpẹ́ yí, Màmá wa MOA ṣe ìkí-ni pàtàkì fún àwọn I.Y.P ti D.R.Y, tí wọ́n fi etí sílẹ̀, tí wọ́n sì ní etí ìgbọràn. Ìkíni tí Màmá wa MOA ṣe […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ Ẹ̀YÁWÓ FÚN I.Y.P

Gbogbo àwa I.Y.P yóò ma dúpẹ́ lọ́wọ́ màmá wa, Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá-Ààfin) fún òmìnira orílẹ̀ èdè wa D.R.Y.  Àyípadà ọ̀tun ti de bá gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) nípasẹ̀ àlàkalẹ̀ ètò tí Olódùmarè gbé lé màmá […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈTÒ ÌGBANISÍṢẸ́

Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbáa (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) ti di orílẹ̀ èdè, gbogbo àgbáyé ló sì ti mọ̀, àti pé orílẹ̀ èdè aṣàkóso-ara-ẹni ni orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá, D.R.Y.  Oríṣiríṣi àǹfààní ló wà fún àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

A DÚPẸ́ LỌ́WỌ́ YÍN

Màmá wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá-Ààfin), ẹni tí Olódùmarè yàn fún Ìgbàlà àwa ọmọ Yorùbá, fi ìmoore gbogbo ọmọ Yorùbá hàn sí àwọn tó ti nfún wa lówó títí di àsìkò yí, àti àwọn tí ó sì tún nfún wa lówó si – èyíinì, àwọn tó nfún orílẹ̀-ede wa, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÀLÀKALẸ̀ FÚN ÀÀBÒ

Màmá Ìran Yorùbá, Olùgbàlà tí Olódùmarè rán sí àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), màmá wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá-Ààfin) ti fọ’hùn sí’ta – lórí àlàkalẹ̀ tí Olódùmarè fún wọn, fún orílẹ̀-èdè wa D.R.Y, fún ètò-ààbò. Màmá wa MOA sọ pé Àlàkalẹ̀ tí ó wà lọ́wọ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ọ̀RỌ̀ SEGILỌLA ṢÌ WÀ NÍ’LẸ̀ O!

Lára àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣe kókó tí màmá wa, Modupẹọla Onitiri-Abiọla (Olóyè Ìyá-Ààfin) bá gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) sọ láìpẹ́ yí, màmá wa MOA sọ̀rọ̀ nípa ilé iṣẹ́ kan tí wọ́n ń pè ní Sẹ̀gilọlá Resources […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌMỌ́TÓTÓ ORÍLẸ̀ ÈDÈ WA

Ìmọ̀tótó borí àrùn, bí ọyẹ́ ṣe nborí oru. Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), ìmòtótó jẹ́ nkan gbòógì tí a kò lè fi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú ní orílẹ̀ èdè wa, láti dènà àìsàn àti àrùn ní àyíká àti agbègbè wa.  Láìsí ìmọ́tótó agbègbè àti àyíká wa, nílé, lóko, […]

Read more