Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌKỌJÁ ÀÀYÈ GIDI

Ìròyìn kan gbé Ipinnu ìjọba agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà jádè nípa ìgbésẹ wọn láti kọ́ ẹnu ibodè sí àwọn òpópónà márosẹ̀ ni ìlú wọn láti lè ma gba owó ọ̀nà lọ́wọ́ àwọn tó nwakọ̀ kọjá níbẹ̀. Bi kò bá ṣe pé wọ́n darukọ àwọn ìlú tó jẹ́ tí Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ PẸ̀LÚ ÌWÀ IBI RẸ̀

Olódùmarè má jẹ̀ẹ́ kí ayé wa dàbí ìlú aríremáṣe nàìjíríà, ìlú tí wọ́n ń fi ìwà ibi yangàn tí wọ́n sì ń gbilẹ̀ nínú rẹ̀, oníkálukú ló ń ṣe òfin lọ́wọ́ ara rẹ̀, òfin kò sí fún olówó, tálíkà nìkan ni ó wà fún, èyí wá fún kálukú láàyè láti ma pa èlòmíràn l’ẹ́kún jayé. […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: KÒ NÍ SÍ ÀYÈ FÚN RÌBÁ

Àlàkalẹ̀ ètò ìsèjọba orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) tí Olódùmarè fún màmá wá, ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla, kò fi àyè sílẹ̀ fún rìbá tàbí owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ rárá, yálà ní ilé iṣẹ́, ní ilé ìwé, nínú ètò òṣèlú àti ní oríṣiríṣi ẹ̀ka. Ẹnikẹ́ni tó bá gbìyànjú láti ṣe lòdì […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AMÚNISÌN ŃṢE’KÚPA ÀWỌN OLÓRÍ

Ìgbàkúgbà tí olórí kan bá ti ń ṣe dáradára fún àwọn orílẹ̀-èdè rẹ̀ ní Áfríkà, ṣe ni àwọn òyìnbó amúnisìn máa ń ṣekúpa irúfẹ́ olórí bẹ́ẹ̀, tàbí kí wọ́n ba ìlú jẹ́ mọ́ọ lọ́wọ́. Ọkùnrin aláwọ̀dúdú kan ni ó sọ ọ̀rọ̀ yí, ní orí ẹ̀rọ Ayélujára TikTok, ìkànnì @africaonepeace.  Ó wá dárúkọ̀ lára àwọn tí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ÌYÀWÓ ILÉ TI DI OLÓṢÓ TÁN

Nínú fọ́nrán kán lórí ayélujára ni a ti ri ọkùnrin báálé ilé kan, tó fi ìkorò-ọkàn kígbe pé owó tí wọn ngbà l’oṣù kò tó láti ra àpò irẹ̀sì kan.  Kí ló fà á tí gbogbo nkan fi rí báyìí, nípasẹ̀ bí ọ̀rọ̀ yí ṣe ta bà wá ní Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

APANIMÁYỌDÀ ỌMỌ ÍBÒ

Ọkùnrin Ìgbò kan tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Emeka Madu, pẹ̀lú àwọn ọmọ Ìgbò ẹgbẹ́ rẹ̀ mẹ́rin, ní ìlú Ìkọ̀tún ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) wa yí, ni a rí fọ́nrán bí ó ṣe nṣe àwọn oògùn nínú ilé àlàpà, tí òògùn náà sì l’ewu. Ìyẹn tilẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ORÍLẸ̀ ÈDÈ D.R.Y KÒ NÍ SÍ LÁBẸ́ ORÍLẸ̀ ÈDÈ KANKAN

Láìsí àní-àní, orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) ti dúró, Olódùmarè ti fún wa ní òmìnira nípasẹ̀ màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla láti ogúnjọ́ oṣù Bélú ẹgbàáọdúnóléméjìlélógún bẹ́ẹ̀ni a ti ṣe ìbúra wọlé fún olórí adelé wá bàbá wa Mobọlaji Ọlawale Akinọla Ọmọkọrẹ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Igbe […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

IMF TI YÁ’WÓ L’ỌWỌ́ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍA RÍ

Bóyá Fúlàní ni; bóyá inkan-kí’nkan tí ìbáà wù kó jẹ́, èyí tí ó pe’ra rẹ̀ ní Alhaji Abubakar Alhaji, tí ó jẹ́ mínisítà ètò ìṣúná ní agbésùnmọ̀mí nàìjíríà ní àkókò ìṣejọba shagari ní ìlú aríremáṣe nàìjíríà náà, sọ pé nṣe ni òun nsun ẹkún fún Nàìjíríà, l’oní, torí pé, ní ẹgbàá ọdún ó dín mẹ́rin-dín-l’ọgbọ̀n, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ọ̀DỌ́BÌNRIN TÓ NÍ ÀÌSÀN JẸJẸRẸ

Ọ̀dọ́bìnrin kan ẹni ọdún méjìlélógún tó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ Fáṣítì ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, D.R.Y, èyí tí ìlú agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà ń fi ipá jẹ gàba lé lórí, ni a gbọ́ wípé ó ní àìsàn jẹjẹrẹ tí ó sì nílò mílíọ̀nù márùndínlógún náírà fún ìtọ́jú. Eléyi gba omijé lójú ẹni. Ó wá di dandan […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ILẸ̀ ỌLỌ́RÀÁ NI ILẸ̀ YORÙBÁ

Tí a bá rí ẹnikẹ́ni tó ń sọ wípé kíni àwa ìran Yorùbá máa jẹ bí a ṣe dá dúró gẹ́gẹ́ bíi orílẹ̀ èdè, a jẹ́ wípé irú ẹni bẹ́ẹ̀ ní ojú ṣùgbọ́n kò fi ríran.  Láìpẹ́ yìí ní a rí fọ́nrán arákùnrin kan tó ń ṣe àfihàn tòmátì tó kórè nínú oko, kìí ṣe […]

Read more