• Oríkò Ilé-Iṣẹ́, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN ALÁGBÁRA AYÉ MÉJÌ

Nínú fọ́nrán kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti rí arákùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Phillips níbi tó ti ń ṣe àlàyé fún Ààrẹ àná ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà bí àwọn orílẹ̀ èdè China ṣe jẹ́ àgbátẹrù rí ra àwọn ilẹ̀ tó ṣe gbòógì fún ètò ọ̀gbìn yíkáàkiri àwọn ibùdó ọmọ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ALÁGBÁRA BÍ ỌLỌ́RUN KÒ SÍ

Alágbára mà ni Ọlọ́run Elédùmarè, ìròyìn kan ló tẹ̀ wá lọ́wọ́ ní ìlú àwọn agbésùnmọ̀mí Naijiria nípa ọmọ ọdún kan tí àwọn ọmọ-ogun ilẹ̀ náà rí nínú igbó Sambisa ti ìyá rẹ̀ tó jẹ́ Ọlọ́run nípè ti jẹrà lati ìdodo dé ẹsẹ̀ rẹ̀, ṣugbọ́n gbogbo igbáàyà rẹ̀ lo ṣe rẹ́gí, tí ọmọdé yi sì ń […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌBÁṢEPỌ̀ PẸ̀LÚ ORÍLẸ̀-ÈDÈ MÍRÀN

Nínú Ìkédé Òmìnira Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, èyí tí ó wáyé ní ogúnjọ́ oṣù Bélú, Ẹgbàá ọdún ó lé méjìlélógún, ọ̀kan nínú àwọn gbòógì gbólóhùn tí ó jáde si àgbáyé, nínú ìkéde náà, sọ báyi: “Àwa Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá ní ìgbàgbọ́ nínú ìbọ̀wọ̀-fa’ra-ẹni, àparò-kan-ò-ga-jùkanlọ, ní ìbáṣepọ̀ orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè. Nítorí èyí, a níi lọ́kàn láti ní ìbáṣepọ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

AFẸ́NIFẸ́BI Ń SUN ẸKÚN KÍKORÒ

Àwọn afẹ́nifẹ́bi, tí wọ́n npe ara wọn ní afẹ́nifẹ́re, tún ti bẹ̀rẹ̀ ẹkún tí wọ́n ti ń sun láti ayébáyé, lórí bí ń kan ṣe bàjẹ́ tó ní ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà wọn. Ṣé kò tilẹ̀ sí ẹnikẹ́ni nínú ẹgbẹ́ òṣì wọn náà ni, tí ọpọlọ rẹ̀ á ti ẹ̀ pé díẹ̀, láti mọ̀ pé òmìnira […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ORÍLẸ̀ ÈDÈ NIGER TÚN TI GBÉ ÌGBÉSẸ̀ AKIN

Tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa orílẹ̀ èdè olórí ire lónìí, iwájú ní orílẹ̀ èdè Niger wà látàrí àwọn ìgbésẹ̀ akin tí wọ́n ń gbé láti bíi ọdún mélòó kan sẹ́yìn. Ìròyìn tí a tún gbọ́ báyìí ni wípé, Orílẹ̀ èdè náà tún ti pá láṣẹ kí àwọn ọmọ ológun orílẹ̀ Germani ó kúrò lórí ilẹ̀ wọn […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ADÉLÉKÈ, AJẸGÀBA, ÌGBÀ YÍ LÀÁRỌ̀

Akọ̀ròyìn kan ló sọ fún wèrè tó fi ipá dúró sí oríkò ilé-iṣẹ́ ìjọba Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) wa, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, èyíinì, èyí tó pera rẹ̀ ní Adémọ́lá Adélékè pé, ìgbàyí làárọ̀? Kò sí ẹni tí ó lè yipadà, Orílẹ̀-Èdè D.R.Y ti kúrò lára Nàìjíríà ní ogúnjọ́ oṣù […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN AKÉKỌ̀Ọ́ ILÉ ÌWÉ GÍGA FÁSITÌ ÌBÀDÀN FI Ẹ̀HÓNÚ WỌN HÀN

Ìròyìn kan jáde pé àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Fásitì Ìbàdàn ti bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn míràn, látàrí àfikún owó ile ìwè wọn. Ilé ẹ̀kọ́ Fásitì yí wà ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá(Democratic Republic of the Yorùbá, DRY) ti ìlú agbèsùnmọ̀mí Naijiria ń fi ipá jẹgàba lórí rẹ̀, ìjẹgàba àwọn agbésùnmọ̀mí náà ló fa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ bí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

K’Á ṢỌ́RA NÍPA OÚNJẸ TÍ A Ń RÀ

Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ńkan ló ń ṣẹlẹ̀ kí àwọn oúnjẹ àti ohun-èlò-ọbẹ̀ tí a ń rà ó tó dé ọ̀dọ̀ wa. A ò mọ èyí tí ó le mú aburú wá níbẹ̀ nítorí èyí, a níláti ṣọ́ra dáradára. Obìnrin kan ni a gbọ́ wípé ó lọ sí ọjà láti lọ ra tòmátì; ṣe ló délé tán, tó […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ÈTÒ ILÉ GBÍGBÉ

Láìpẹ́, láìjìnnà, orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) yóò di àpéwò káàkiri àgbáyé látàrí àwọn ohun àrà-meèrírí tí yóò máa ṣẹlẹ̀ lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan ní orílẹ̀ èdè wa nípasẹ̀ ọgbọ́n, ìmọ̀ àti òye tí Olódùmarè fún màmá wá, iya ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla, lára àwọn ohun tí màmá wa ti máa ń […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ỌGBỌ́N LÁTI FI OWÓ-ORÍ ṢE IBI FÚN ÁFRÍKÀ

Inúnibíni kò kan tí àìmọ̀ ìwà hù. Èyí ló d’ífá fún bí àwọn ẹni-ibi òyìnbó-amúnisìn ṣe ńfi ojojúmọ́ wá ọ̀nà láti fí Áfríkà sí abẹ́ ìsìnrú wọn láì sí ẹ̀ṣẹ̀ kankan tí Áfríkà ṣẹ̀ wọ́n. Òyìnbó ṣáà ń bínú wa.  Àbí kí ló kan òyìnbó pẹ̀lù owó-orí àwọn orílẹ̀-èdè olómìnira ní ilẹ̀ adúláwọ̀? Tani kò […]

Read more