ILẸ̀ GẸ̀Ẹ́SÌ, OLÈ..
Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, olè tí ó fi ipá àti àrékérekè gba ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ilẹ̀ káàkiri àgbáyé, tí wọ́n sì jẹgàba sí’bẹ̀ pẹ̀lú ìkónil’ẹrú amúnisìn tí wọ́n nṣe káàkiri àgbáyé nígbànáà-l’ọhún, títí di àkókò yí pàápàá, ti wá j’ọwọ́ àwọn Erékùṣù Chagos báyi, fún Orílẹ̀-Èdè Mauritius, èyí tí ó wà ní Agbami-Òkun apá ìlà-oòrùn Áfríkà. Ṣebí Mauritius l’ó […]