Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌBA ÍLẸ̀ YORÙBÁ NÍGBÀTÍ AMÚNISÌN DÉ

Ilẹ̀ Yorùbá jẹ̀ orílẹ̀ èdè olómìnira aṣèjọba ara ẹni láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ wa. Nígbàtí àwọn òyìnbó amúnisìn wọlé dé, wọ́n bá wa pé ọba àti àwọn ìjòyè ló ńṣe kòkárí ìṣàkóso ìṣèjọba nígbà náà. Àrékérekè ati ẹ̀tàn ni àwọn aláwọ̀ funfun yìí lò láti sọ ara wọn di amùnisìn lóri ìran Yoruba. Àwọn òyìnbó yí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: KÒ SÍ ÀYÈ FÚN AMÚNISÌN MỌ́

Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) ti dúró, yálà ọ̀tá fẹ́ tàbí wọ́n kọ̀. Ó ti pẹ́ tí ìran Yorùbá ti ń j’ìyà lọ́wọ́ àwọn amúnisìn, ṣé ti àwọn ọba ni ká sọ ni, àwọn tí wọ́n pe’ra wọn ní olóṣèlú tàbí àwọn  amúnisìn láti ìta. Ẹni gb’épo lájà […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: Ẹ̀KỌ́ TÓ YÀTỌ̀ SÍ TI ẸRÚ

Nínú àwọn ọ̀rọ̀ tí Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá máa ń bá wa sọ, wọ́n ti fi yé wa pé gbogbo ńkan tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ kọ́ ní ẹ̀kọ́ ti òyìnbó, tí wọ́n sì ń tìtorí èyí pe’ra wọn ní ‘elite,” àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, tí a bá ko jọ, kò kúkú ju ìdajì ojú-ewé kan ní […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌRÌN-ÀJÒ ÌRAN

Lóotọ́ àti ní Òdodo, a ti dé ibi tí a nlọ – a ti di Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), a sì ti bẹ̀rẹ̀ sí lo agbára ìṣèjọba-ara-ẹni wa, láti ọjọ́ kéjìlá oṣù igbe, ẹgbàá-ọdún, ó lé mẹ́rin-lé-lógún tí a wà nínú rẹ̀ yí, pẹ̀lú gbígbé ìjọba wa wọlé, nígbàtí a ṣe ìbúra-wọlé fún […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ ÀÀBÒ TÓ PÉYE

Ọ̀rọ̀ ètò ààbò jẹ́ ohun pàtàkì tí a kò sì gbúdọ̀ fi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú, nítorí wípé, kò sì ohunkóhun tí ènìyàn leè ṣe  nínú ìbẹ̀rù àti àìbalẹ̀ ọkàn. Ìjọba tó bá fẹ́ ìdàgbàsókè fún orílẹ̀ èdè rẹ̀, yóò rí ọ̀rọ̀ ààbò gẹ́gẹ́ bíi ohun àkọ́kọ́ nínú ètò ìsèjọba  rẹ̀ tí ó sì gba àmójútó […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

BÍ ÀWỌN ỌBA ILẸ̀ YORÙBÁ ṢE PÀDÁNÙ ADÉ WỌN

Ọba ‘bìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ó ndarí ìlú agbèsùnmọ̀mí nàìjíríà fún ọdún mẹ́ta lẹ́yìn òmìnira òfegè tí wọ́n fún ìlú apanilẹ́kún jayé náà, tí ó túmọ̀ sí pé abẹ́ àkóso ìjọba ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ìlú náà ṣì wà. Ní ẹgbàá ọdún ó dín ḿẹ́tàdínlógójì, àwọn olórí ìlú náà gbé ìgbésẹ láti yọ ọwọ́ ọba ‘bìnrin […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌDÀGBÀSÓKÈ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ

Káàkiri àgbáyé ni wọn yóò ti mọ orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) gẹ́gẹ́ bíi orílẹ̀ èdè àrà ọ̀tọ̀ nípasẹ̀ àwọn ohun àrà-meèrírí tí yóò máa ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè wa. Ní kété tí àwọn adelé wa bá ti wọlé sí oríkò ilé iṣẹ́ ìjọba wa ní àwọn ìpínlẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ẹ̀YIN TÍ Ẹ PERA YÍN L’ỌBA, INÁ TI JÓ YÍN!

Ṣébí Yorùbá ló sọ pé ibi tí a bá ti pè ní Orí, a kìí fi ibẹ̀ tẹ’lẹ̀; ṣùgbọ́n, báyi, ó wá ṣe’ni láanú o, pé, àwọn kan ní ilẹ̀ Yorùbá, wọ́n ti di ẹni àbùkù, pátápátá, látàrí pé, bí Ọmọ Yorùbá ṣe gbé wọn gẹ-gẹ-gẹ, wọ́n fún’ra wọn sọ ara wọn di ẹni àbùkù, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: D.R.Y KÒ NÍ JẸ GBÈSÈ

Màmá Ìran Yorúbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nfi yé wa pé ìkan nínú àwọn ọ̀nà tí àwọn amúnisìn fi máa nmú àwọn orílẹ̀-èdè ní ẹrú, ni nípa gbèsè jíjẹ. Àwọn ni wọ́n á fa orílẹ̀-èdè náà pé kó wá yáwo; àwọn ni wọ́n a sọ fun bí ó ṣe máa ná owó náà, àti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AMÚNISÌN ÀTI ÈRÒǸGBÀ IBI

Àtunbọ̀tán ìwà ìkà àti ìjẹgàba àwọn amúnisìn ṣi kù lára àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ilẹ̀ Yorùbá nítorí pé, wọ́n ti jogún ìwà ọ̀dájú yìí lára àwọn amúnisìn, tí wọ́n tan àwọn bàbá nla wa jẹ. Lẹ́hìn ọ̀rẹyìn ni àwọn amúnisìn rò wípé, óṣeṣe fún wọn láti gba ìlẹ̀ àwa ọmọ Yorùbà fún ara wọn, tí wọ́n si […]

Read more