DÓKÍTÀ KỌJÁ ÀYÈ RẸ̀, L’ÁTÀRÍ ÌJẸGÀBA
Ṣebí ìjẹgàba ìjọba agbésùnmọ̀mí nàìjíríà, lórí ilẹ̀ Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), ló fa ìwà ọmọ-ìta tí oníṣègun òyìnbó kan hù ní ilé-ìwòsàn ìjọba, ní Ijaye, ìlú Abẹ́òkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn orílẹ̀-èdè D.R.Y. Ṣe ni àgbà dókítà ọ̀hún, ẹni tó jẹ́ Abánidámọ̀ràn nínú iṣẹ́ eegun-títò,bu ìfọ́’tí lu akẹ́ẹ̀kọ́ nọ́ọ̀sì kan ní […]